Khanyi Mbau | |
---|---|
Mbau ní osù kejìlá ọdún 2017. | |
Ọjọ́ìbí | Khanyisile Mbau 15 Oṣù Kẹ̀wá 1985 Soweto, South Africa |
Orílẹ̀-èdè | South African |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 2004–present |
Website | https://mykhanyimbau.com |
Musical career | |
Irú orin | |
Instruments | Vocals |
Labels |
|
Associated acts | |
Kanyisile Mbau(bíi ni ọjọ́ kẹẹdọgbọn oṣù kẹwàá ọdún 1986) jẹ́ òṣèré àti atọkun ètò lórí tẹlẹfíṣọ̀nù ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà. Mbau di gbajúmọ̀ nítorí ipa doobsie tí ó kó nínú eré Muvhango ni ọdún 2004.[2] Ó ṣe atọkun fun ètò The Scoop ati The Big Secret.[3]
Wọ́n bí Khanyasile ni ọdún 1995. Ìyá rẹ, Lynette Ṣíṣí Mbau ṣiṣẹ́ pẹlu ilé ifówópamọ́ tí Barclay Bank. Ìyá rẹ àti bàbà rẹ kò tí ṣe ìgbéyàwó nigba tí wọn fi bí Khanyasile, bàbà rẹ kò gbà á gẹ́gẹ́ bí ọmọ rẹ̀, ṣùgbọ́n ó se ìsọmọlórúkọ fun.[4]
Ní ọdún 2004, wọn fi Mbau rọ́pò Lindiwe Chibi láti kó ipa Doobsie nínú eré Muvhango.[5] Lẹ́yìn ọdún kan, wọn lé kúrò nítorí pé ó ti féràn àríyá ju. Ní ọdún 2006, ó darapọ̀ mọ́ eré Mzansi[6]. Ní ọdún 2012, ó ṣe adájọ́ fún ètò kejì tí Turn It Out, èyí tí SABC gbé kalẹ̀. Ó gbà àmì ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bí òṣèré tó dára jù lọ fún ipá tí ó kó nínú eré Red Room láti ọ̀dọ̀ South Africa International Film Academy Awards ní ọdún 2019.[7]
Ọdún | Àkólé eré | Season | Ipa tí ó kó | |
---|---|---|---|---|
2019 | The Scoop | Season 1 - 3 | Host - herself | |
2014 -20 | Katch It With Khanyi | Season 1 - 3 | Host - herself | |
After 9 | Season 1 | Zee | ||
2018 | Isithembiso | Season 2 | Herself | |
2015 - 2016 | Ashes to Ashes | Season 1 | Pinki | |
aYeYe | Season 1 | Thenjiwe | ||
Check - Coast | Season 1 | |||
eKasi: Our Stories[8] | Season 5 | Thabiso/Thandisiwe | ||
I Am | Season 1 | Herself | ||
Like Father Like Son[9] | Season 1 | Sindisiwe Sibeko | ||
Muvhango | Season 1 | Doobsie | ||
2018 - 2019 | Uzalo | Season 4 -5 | Dinekile aka Lady Die | |
My Perfect Family | Season 3 | Herself | ||
Mzansi | Season 2 | Mbali | ||
Mzansi Love - Kasi Love | Season 2 | Kgomotso | ||
Mzansi Love - Big City Love | Season 3 | Lebo Kgosi | ||
Reality Check | Season 1 | Herself | ||
Scandal | Season 1 | Katlego | ||
Skwizas | Season 3 | Mimi | ||
Strictly Come Dancing | Season 7 | Celebrity dancer - herself | ||
The Close Up | Season 4 | Herself | ||
The Comedy Central Roast | Season 7 | Roaster - herself | ||
The Lab | Season 1 - 2 | Kgomotso/Busi | ||
The South African Film and Television Awards | Season 8 - 10 | Presenter - herself | ||
The South African Music Awards | Season 22 - 23 | Host/presenter - herself | ||
Tropika Island of Treasure - Thailand | Season 3 | Herself | ||
Turn it Out - Street Battle | Season 2 | Guest judge - herself |