Klaus Biemann | |
---|---|
Ìbí | Innsbruck, Austria | Oṣù Kọkànlá 2, 1926
Aláìsí | June 2, 2016 | (ọmọ ọdún 89)
Pápá | Mass spectrometry |
Ilé-ẹ̀kọ́ | Massachusetts Institute of Technology |
Ibi ẹ̀kọ́ | University of Innsbruck Ph.D. Organic Chemistry 1951 |
Doctoral students | John M. Hayes[1] |
Ó gbajúmọ̀ fún | Mars Viking mass spectrometer[2] |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | Benjamin Franklin Medal in Chemistry (2007) NASA Exceptional Scientific Achievement Medal (1977)) |
Klaus Biemann (Ọjọ́ kejí Oṣù kọkànlá Ọdún 1926 – Ọjọ́ kejí Oṣù kẹfà Ọdún 2016)[3][4] jẹ́ ọ̀jọ̀gbón onímọ̀ chemistry ní Massachusetts Institute of Technology. Ìṣé rẹ̀ dá lórí ìgbékalẹ̀ onínọmbà ní organic àti biochemistry. Wọ́n ti pèé ní "Bàbá organic mass spectrometry."[5]