Kolkhoznitsa melon, je eso ti a tun mo sí egusi ti awọn akojọpọ agbe obirin, o je eso egusi ninu ẹyà Cucumis ti o tan mo Russia ,ti a tun fi mo awon ara ile Amerika ni ọdún 1993.[1]
A koko gbìn ni ọdún 1930s nipasẹ Russian gardener , fun akoko kekere kan. Igba ti o ya lotan dé ile Europe bi Ukraine,ki o to wa dé ile Amerika .[2] Rindi rẹ Tirin ati wipe o ni awo golden orange,ẹran ara rè sí funfun ati dense.O ri roboto sí oblong ni irisi. Oorun rẹ dùn àti pé o to 3 pounds (1.4 kilograms). Àwọn irúgbìn yìí je eso ti o tutu ti o sì lè pẹlu,o dé ndagba ni averagi egusi meta ni asiko kan[1]
A so Kolkhoznitsa melon ni orúkọ yìí nipa ajokopo agbe ni ile Soviet Union ti a mo sí kolkhoz.
Eso irúgbìn yìí wa jakejado ayelujara.