Korede Bello | |
---|---|
Background information | |
Ọjọ́ìbí | 29 Oṣù Kejì 1996 Lagos State, Nigeria |
Irú orin | Àdàkọ:Csv |
Occupation(s) | Àdàkọ:Csv |
Years active | 2009–present |
Labels | Mavin Records |
Associated acts | |
Website | koredebello.com |
Korede Bello (tí a bí ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n, oṣù kejì, ọdún 1996) ọ̀kọrin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti akọrin sílẹ̀.[1] Ó tẹwọ́bọ̀wé pẹ̀lú Mavin Records ní ọdún 2014. Orin rẹ̀ "Godwin" ló mu bọ́ sí gbangba.[2]
Korede (Èyí tí ó túǹmọ́ Ko Ire Wá) jẹ́ ọmọ tí tí wọ́n bí sí ìlú Èkó, ibè náà ló tí ká ìwé alákọ̀bẹrẹ̀ àti ilé ìwé Sẹ́kọ́ńdìrí. Ó bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣeré ìdárayá nígbà tí ó wá ní ọmọ ọdún Méje, orúkọ rẹ ní gbà náà sì ń jẹ́ "African Prince"
Nígbà tí ó wá ní ilé ìwé alákọ̀bẹrẹ̀, Korede Bello kọ Orin àkọkọ́ lẹ́yìn tí ó dá egbé kàn sílè pẹlú ọ̀rẹ rẹ̀.[3] Ó mú iṣẹ orin lokunkundu lẹyìn tí ó kó àwọn Orin nínú Studio [4] Ni ilé ìwé Gírámà, o ṣé àwó orin tí óò pé àkọlé rẹ̀ ni 'FOREVER' èyí tí ó ẹ́ akọkọ. O tẹsiwaju nínú èkó rè láti lọ mọ nípa Ìmọ̀ ibi-ibaraẹnisọrọ (Mass communication), ọ sí ní Certificate Higher National Diploma. Korede Bello jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ tí iléesẹ́ tí Institute Of Information Management.[5][6]
Lẹ́yìn tí ó Àwó àkọkọ́ jáde, èyí tó o gbà oríyìn tí odará, ní ọgá rẹ Casmir Uwaegbute mú hàn ( Don Jazzy) èyí tí wọ́n jọ gbìmọ kọ orin mìíràn, tí inú Don Jazzy sí dùn sí.[7] Ni ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n, oṣù Kejì ọdún 2014, ni ó wọ Mavins Record lábẹ́ èyí tí o tún gbé àwọn orin tó jẹ́ gbajùmọ̀ bíi " African Princess" àti " Godwin"[8] Lówó lọwọ́ ó ń ṣe àkọ́kọ́ ìṣiṣẹ́ Album, èyí tí ó sí fí ÀṢÀ àti 2face idibia ṣe àwọn àwòrán ẹnití tí ó ń rí ìmísí láti ará orin tí wọ́n tí kò sẹ́yìn.[9]
Kóredé Bello ti ṣe awọn oríṣiríṣi iṣẹ Ọmọnìyàn bí "Project Pink Blue walk" fún ìmọ lori Àrùn Jẹjẹrẹ (Cancer) ni ìlú Abuja, ni ọdún 2015 . [10][11][12] àti 2017
Title | Year | Release date |
---|---|---|
"African Princess" | 2014 | 28 February 2014 |
"Dorobucci" (with Don Jazzy, Tiwa Savage, Dr SID, D'Prince, Reekado Banks and Di'Ja) |
1 May 2014 | |
"Adaobi" (with Don Jazzy, Reekado Banks and Di'Ja) |
27 May 2014 | |
"Cold Outside" | 15 August 2014 | |
"Looku Looku" (with Don Jazzy, Tiwa Savage, Dr SID, D'Prince, Reekado Banks and Di'Ja) |
31 October 2014 | |
"Jingle Bell" | 25 December 2014 | |
"Godwin" |
2015 | 28 January 2015 |
"Jantamanta" (with Don Jazzy Tiwa Savage, Dr SID, D'Prince, Reekado Banks and Di'Ja) |
27 October 2015 | |
"Romantic" (with Tiwa Savage) |
December 2015 | |
"Mungo Park" | 2016 | 7 May 2016 |
"One & Only" | 26 May 2016 | |
"Do Like That" | 13 September 2016 | |
"Butterfly" | 2017 | 17 May 2017 |
"My People" | 1 September 2017 | |
"Melanin Popping" | 2018 | 18 January 2018 |
"Work it" | 1 April 2018 | |
"So te" | 7 May 2018 | |
"2geda" | 22 May 2018 | |
"Champion" | 29 September 2018 | |
"Bless Me" | 30 September 2018 | |
"Mr. Vendor" | 2019 | 26 April 2019 |
"Sun Momi (Only You)" | 2020 | 12 February 2020 |
Year | Award ceremony | Prize | Recipient/Nominated work | Result | Ref |
---|---|---|---|---|---|
2014 | Nigeria Teen Choice Awards 2014 | Most Promising Music Act To Watch | Himself | Gbàá | [13] |
2015 | 4th Annual Golden Icons Academy Movie Awards | Best Song of the Year | "Godwin" | Gbàá | [14] |
2015 Nigeria Entertainment Awards | Hottest Single of The Year | Wọ́n pèé | [15] | ||
Best New Act | Himself | Wọ́n pèé | [15] | ||
2016 | The Headies 2015 | Best Pop Single | "Godwin" | Gbàá | [16] |
Song of The Year | Wọ́n pèé | [17] | |||
Next Rated | Himself | Wọ́n pèé | [17] | ||
2016 City People Entertainment Awards | Pop Artiste of the Year | Himself | Gbàá | [18] | |
2016 Nigeria Entertainment Awards | Best Collaboration | "Romantic" (featuring Tiwa Savage) | Wọ́n pèé | [19] | |
9th Nigeria Music Video Awards | Best Contemporary Afro Video | "Godwin" | Gbàá | [20] |
|url-status=
ignored (help)[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
|url-status=
ignored (help)