Lagbaja tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Bísádé Ológundé tí a bí ní ìlú Èkó ni ọdún 1960 jẹ́ gbajúgbajà akọrin afrobeat ọmọ orílè èdè Nàìjíríà. Gbogbo ènìyàn mọ akọrin yí sí Lágbájá nítorí wípé ó jé ẹni tí ó fẹ́ràn láti máa lo ìbòjú láti dáàbò bo ara rẹ kí wọn má le dáa mọ̀.[1][2] Ó gbàgbọ́ nínú àtúntó ìlú láti ipasẹ̀ orin kíkọ.
Lagbaja
Glo Oga SIM - The Unrivaled Big Boss of Data ft. Lagbaja
Background information
Orúkọ àbísọ
Bisinuade Ologunde
Irú orin
Afrobeat
Occupation(s)
Singer-songwriter, instrumentalist, founder of Opatradikoncept
Ologunde mú orúkọ ìnagije rẹ̀ "Lagbaja" látara "Jane Doe" tí ó túnmọ̀ sí en t́ ó fi ojú rẹ̀ pamọ́. Orúkọ rẹ̀ yìih hàn nínú ìmúra rẹ̀ àti ìbòjú tó fi bojú. Ó dá ẹgbẹ́ akọ́kọ́ rẹ̀ silẹ̀ ní ọdún 1991 ní ìpínlè Èkó.[3][4]