Lilian Adera

Lilian Adera
Personal information
OrúkọLilian Odaa Adera
Ọjọ́ ìbí7 Oṣù Kàrún 1994 (1994-05-07) (ọmọ ọdún 30)
Ibi ọjọ́ibíKisumu, Kenya
Playing positionDefender
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
Vihiga Queens
National team
Kenya women's national football team
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals).

Lilian Adera jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 7, may ni ọdun 1994. Agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi defender fun team apapọ awọn obinrin ilẹ kenya[1][2][3].

  • Lilian kopa ninu Nation Cup awọn obinrin ilẹ afirica[4].
  1. https://fbref.com/en/players/3bc3e00b/Lilian-Adera
  2. https://globalsportsarchive.com/people/soccer/lilian-adera/157005/
  3. https://m.goalzz.com/default.aspx?player=143922
  4. https://www.playmakerstats.com/player.php?id=777967