Lilian Esoro | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Lilian Esoro 10 Oṣù Kẹta 1982 Imo State, Nigeria |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Naigiria |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Abuja |
Iṣẹ́ | Òṣèré |
Ìgbà iṣẹ́ | 2006–present |
Notable work | Tinsel |
Lilian Esoro tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹwàá oṣù Kẹta ọdún 1982.[1] jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé àti sinimá ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Wọ́n yàn án fún ipò òṣèrébìnrin aláwàdà tó peregedé jùlọ nínú amì-ẹ̀yẹ ti '2013 Africa Magic Viewers Choice Awards'.[2][3]
Esoro kẹ́kọ́ jáde nípa ìmọ̀ Ìṣèlú ní Yunifásitì ti Àbújá.[4]
Lilian bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré ṣiṣẹ́ ní ọdún 2005, nígbà tí ọ̀rẹ́ rẹ̀ Bovi fun ní ayè láti kópa nínú eré àtìgbàdégbà ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ tí wọ́n pe àkọ́lé rẹ̀ ní Clicn Matters, tí ó sì kópa bí Nọ́ọ̀sì Abigail nínú eré náà..[4][5] Esoro wà lára àtòjọ àwọn òṣèré tunrun tó peregedé jùlọ ní Nollywood gẹ́gẹ́ bí Ìwé-ìròyìn Vanguard ṣe ṣe àtòjọ wọn. [6]
Ìpínlẹ̀ Èkó ni Esoro dàgbà sí, [7] Ó kọ́ nípa Integrated Science ní ilé-ẹ̀kọ́ 'Bida Polytechnic'.[8][9][10]
Ó ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú Ubi Franklin, ọ́ Esoro ti bí àwọn ọmọ tẹ́lẹ̀ kí tó ṣe ìgbéyàwó ní ọdún 2015.[11]
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)