Lyta | |
---|---|
![]() Lyta in an all-white photo shoot | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Opeyemi Babatunde Rahim |
Ọjọ́ìbí | Ajegunle, Lagos, Nigeria |
Irú orin | |
Occupation(s) |
|
Years active | 2018–present |
Labels | Rafat Music[1] |
Associated acts |
Babatunde Rahim, tí orúkọ ìnagijẹ̀ rẹ̀ ń jẹ́ Lyta, jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó tẹwọ́bọ̀wé iṣẹ́ pẹ̀lú YBNL Nation, ní ọdún 2018, àmọ́ ó kúrò lẹ́yìn èdè-àìyedè tó wáyé láàárín òun àti ẹni tó ní ilé-iṣẹ́ náà, ìyẹn Olamide.[2] Ó ṣàgbéjáde àwo-orin olórin márùn-ún, EP Id, ní ọdún 2019.[3]
|url-status=
ignored (help)