Mama Insurance

Mama Insurance jẹ́ fíìmù Nàìjíríà ti ọdún 2012, tó dá lórí onílé lan tó kanra mọ́ àwọn ayálégbé rẹ̀. Victoria Island ni wọ́n ti ya fíìmù yìí, olùdarí rẹ̀ sì jẹ́ tí Liz Da-Silva sì gbé é jáde.[1][2]

Fíìmù náà dá lórí obìnrin onílé kan tó máa ń kanra púpọ̀, tí àwọn ayálégbé rẹ̀ sì jẹ́ àwọn obìnrin tó ń ṣe oríṣiríṣi iṣẹ́, tọ́ sì ní ìgbé ayé ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀. Ìfẹ́ tó ní sí ọ̀kan lára wọn ló kó o sínú wàhálà nítorí pé ìyẹn jẹ́ oníjìbìtì.[4][5]

Wọ́n yan Ayo Mogaji fún òṣèré tó dára jù lọ fún ìkópa rẹ̀ nínú fíìmù yìí ní ayẹyẹ YMAA tí ó wáyé ní ọdún 2014.[6][7]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Actors should have a back-up plan — Liz Da Silva". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-01-14. Retrieved 2022-08-01. 
  2. Akintomide, Akinnagbe (2011-08-11). "LIZ DA SILVA SHOOTS ALL FEMALE CAST MOVIE". Modern Ghana (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-01. 
  3. "Odunlade Adekola, Fathia Balogun shine at Yoruba Movie Academy Awards". The Nation Newspaper (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2014-04-05. Retrieved 2022-08-01. 
  4. "LIZ DA SILVA SHOOTS ALL FEMALE CAST MOVIE". www.thenigerianvoice.com. Retrieved 2022-08-01. 
  5. Akintomide, Akinnagbe (2011-08-11). "LIZ DA SILVA SHOOTS ALL FEMALE CAST MOVIE". Modern Ghana (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-01. 
  6. Ayobami, Abimbola (2013-05-27). "Top Yoruba actors’ battle to win at the Yoruba Movie Academy Awards". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-01. 
  7. "Fathia Balogun, Odunlade Adekola shine @ Yoruba Movie Academy Awards 2014". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2014-04-02. Retrieved 2022-08-01.