Mamarumo Marokane | |
---|---|
Marokane in 2019 | |
Ọjọ́ìbí | c. 1996[1] |
Orílẹ̀-èdè | South African |
Ẹ̀kọ́ | CityVarsity School of Media and Creative Arts |
Iṣẹ́ |
|
Height | ruben aguirre is 6’7” |
Mamarumo Marokane (bí ní. 1997) jẹ́ Òṣèré àti Òlùṣètò South African. Wọ́n mọ̀ ọ́ fún ìfarahàn rẹ̀ ní Shadow and MTV Shuga.
Wọ́n bí Marokane ní ọdún 1996 láìmọ̀ àsìkò gan-an.[1] Ó kàwé ní CityVarsity School of Media and Creative Arts. Ó lè sọ èdè Gẹ̀ẹ́sì, èdè Sepedi àti èdè Setswana.[2]
Lọ́wọ́ ó ṣe Vuvu lórí àbùkù pẹ̀lú àwọn ọmọ méjì kan látara ọ̀rẹ́kùnrin tó fẹ́ sẹ́yìn tí orúkọ rẹ̀ jẹ́ Nhlamulo. Marokane gba òkìkí látara àfihàn rẹ̀ nínu eré-ẹlẹ́sẹsẹ Shadow[3] àti lórí MTV Shuga níbi tí ó ti ṣe Dineo.[4]
Ní oṣù kejì ọdún 2020, Marokane gba ipò tàbí orúkọ gẹ́gẹ́ bí àwọn Òṣèré mẹ́rin tí ó ṣìṣè dìde la tọwọ́ Pearl Thusi ní Cosmopolitan South Africa.[1] Ó dára pọ̀ mọ́ àwọn Òṣèré ọlọ́wọ̀ bí nòm̀bà díẹ̀ fún eré lálẹ́ ẹlẹ́sẹsẹ tí wọ́n pè ní MTV Shuga Alone Together tí ó ṣe àwọn àfihàn ìṣòro Coronavirus ní ọjọ́ ogún oṣù kẹ́rin, ọdún 2020.[5][6]
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)