Ilẹ̀ gbígbẹ Màmbíllà jẹ́ òkè ní ìpínlẹ̀ Tàrábà ní Orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ilẹ̀ náà jẹ́ ìtẹ̀síwájú àrìwá ti orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ti àwọn òkè gíga Bameńdà ní orílẹ̀ èdè kamerúúnù .
Mambilla Plateau náà ní àgbède ìgbẹ́ga tí ọ́ tó bií 1,600 metres (5,249 ft) ní èyí tí ó sọ di òkè tó ga jù Nàìjíríà. Àwọn abúlé rẹ̀ wa ̀ni ́ orí òkè tí ó gbọ́́dọ̀̀ ga kéré jù bíi 1,828 metres (5,997 ft) lókè ìpele omi òkun. [1]
Die ninu awon oke nla ti o yiika ga ni 2,000 metres (6,562 ft) giga, bii Chappal Waddi ( ti oruko ti o ye si nje : Gang) eyiti o ga niwon bii 2,419 metres (7,936 ft) loke ipele omi okun. O je oke ti o ga julo ni Naijiria.. [2] ati ooke ti o ga julo ni Iwo-oorun Afirika ti awon oke nla Kameruunu, gege bii oke Kameruunu.