Manning Marable |
---|
Marable in 2007 |
Ọjọ́ìbí | William Manning Marable (1950-05-13)Oṣù Kàrún 13, 1950 Dayton, Ohio, U.S. |
---|
Aláìsí | April 1, 2011(2011-04-01) (ọmọ ọdún 60) New York City, New York, U.S. |
---|
Iléẹ̀kọ́ gíga | |
---|
Olólùfẹ́ | Leith Mullings |
---|
William Manning Marable (May 13, 1950 – April 1, 2011)[1] ọ̀mọ̀wé ará Amẹ́ríkà. Marable jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ètò ìgboro, ìtàn àti Àwọn Ẹ̀kọ́ àwọn ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà ní Yunifásítì Kòlúmbíà.[1] Marable ló jẹ́ ọlùdásílẹ̀ àti olùdarí Ilé-ẹ̀kọ́ fún Ìwadìí nínú àwọn Ẹ̀kọ́ àwọn ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà.[2] Ó kọ ìwé tó pọ̀, ó sì kópa nínú akitiyan òṣèlú onílọsíwájú. Kí ó tó kú ní ọdún 2011, ó ti parí ìwé-ìgbésíayè lórí Malcolm X tí àkọlẹ́ rẹ̀ únjẹ́ Malcolm X: A Life of Reinvention (2011),[3] èyí tí Marable gba Ẹ̀bùn Pulitzer fún Ìtàn fún ní ọdún 2012 lẹ́yìn tí ọ́ kú.[4]
- ↑ 1.0 1.1 Grimes, William. "Manning Marable, Historian and Social Critic, Dies at 60", New York Times, April 1, 2011. Retrieved April 2, 2011.
- ↑ "FOUNDING DIRECTOR | IRAAS Institute for Research in African-American Studies". iraas.columbia.edu (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2017-05-02. Retrieved 2017-05-10.
- ↑ Goodman, Amy. Manning Marable on "Malcolm X: A Life of Reinvention" via Democracy Now!, May 21, 2007. Retrieved April 2, 2011
- ↑ "The late Manning Marable wins history Pulitzer; no fiction prize given". The Washington Post. Associated Press. April 16, 2012. https://www.washingtonpost.com/national/the-late-manning-marable-wins-history-pulitzer-no-fiction-award-for-first-time-in-35-years/2012/04/16/gIQADJIzLT_story.html. Retrieved April 16, 2012.