Mariam Ndagire | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 16 Oṣù Kàrún 1971 Kampala, Uganda |
Orílẹ̀-èdè | Ugandan |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Uganda |
Ẹ̀kọ́ |
|
Iṣẹ́ | Singer, film producer, actress, scriptwriter, film director |
Gbajúmọ̀ fún | Music and film production |
Mariam Ndagire (bíi ni ọjọ́ kerìndínlọ́gún oṣù karùn-ún ọdún 1971) jẹ́ olórin, òṣèré àti olùdarí eré lórílẹ̀-èdè Uganda.[1][2][3]
Wọ́n bí Mariam sí ìlú Kampala ní orílẹ̀ èdè Uganda sí ìdílé Sarah Nabbutto àti Prince Kizito Ssegamwenge. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Buganda Road Primary School àti Kampala High School kí ó tó tẹ̀ síwájú sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Makere University.[4]
Ndagire bẹ̀rẹ̀ eré orí ìtàgé nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́ẹ̀dógún. Ó darapọ̀ mọ́ Black Pearls ní ọdún 1987, ibẹ̀ sì ni ó ti kọ eré àkọ́kọ́ rẹ tí ó pe àkọlé rẹ̀ ní Engabo Y'addako. Òun àti Kato Lubwama àti Ahraf Simwogerere jọ dá ẹgbẹ́ Diamonds' Ensemble kalẹ̀.[5] Ní ọdún 2015, ó jẹ́ ìkan lára àwọn tí ó ṣe adájọ́ fún ètò àmì ẹ̀yẹ tí AFRICA MAGIC VIEWERS' CHOICE AWARDS AMVCA gbé kalẹ̀. Ní ọdún 2019, ó jẹ́ ìkan lára àwọn tí ó ṣe adájọ́ fún GOLDEN MOVIE AWARDS AFRICA.
Ọdún | Nominated work | Award | Category | Èsì |
---|---|---|---|---|
2013 | WHERE WE BELONG | Uganda Film Festival Award | Best Cinematography | Yàán |
2013 | WHERE WE BELONG | Uganda Film Festival Award | Best Sound | Yàán |
2017 | BA-AUNT | Pearl International Film Festival | Best TV Drama | Gbàá |
2017 | NSAALI | Pearl International Film Festival | Best Actress "Dinah Akwenyi" | Yàán |
2017 | NSAALI | Pearl International Film Festival | Best Indigenous Language Film | Yàán |
2017 | NSAALI | Pearl International Film Festival | Best Sound | Yàán |
2017 | NSAALI | Pearl International Film Festival | Best Screenplay "Mariam Ndagire" | Yàán |
2017 | NSAALI | Pearl International Film Festival | Best Director "Mariam Ndagire" | Yàán |
2017 | NSAALI | Pearl International Film Festival | Best Supporting Actor "Sebugenyi Rogers" | Yàán |
2017 | NSAALI | Pearl International Film Festival | Best Young Actor "Nalumu Shamsa" | Yàán |
2017 | NSAALI | Pearl International Film Festival | Best Young Actor "Dinah Akwenyi" | Yàán |
2017 | NSAALI | Pearl International Film Festival | Best Feature Film | Yàán |
2018 | BA-AUNT | Zanzibar International Film Festival | Best TV Drama | Yàán |