Medikal | |
---|---|
Orúkọ àbísọ | Samuel Adu Frimpong |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | MDK, MedikalByK, Medikal |
Ọjọ́ìbí | April 5, 1994 Accra, Ghana |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Sowutuom, Accra Ghana |
Aláìsí | Error: Need valid death date (first date): year, month, day |
Irú orin | |
Occupation(s) |
|
Years active | 2014–present |
Labels | Beyond Kontrol |
Associated acts |
Samuel Adu Frimpong (tí wọ́n bí ní ọjọ́ karùn-ún oṣù Kẹrin, ọdún 1994), tí ó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bí i Medikal, jẹ́ olórin ilẹ̀ Ghana tí wọ́n bí sínú ìdílè Portia Lamptey àti James Frimpong ní Sowutuom, ní Accra.[1][2]
Ó wá láti Sowutuom, ní Accra, Ghana. Medikal àti Sarkodie jẹ́ olórin tí wọ́n yàn jù lọ fún ìgba àmì-ẹ̀yẹ ní ọdún 2017 fún Ghana Music Awards. Ní ọdún 2018, ó farahàn lórí ètò Tim Westwood.[3][4][5] Medikal gba ẹ̀kọ́ girama rè ní Odorgonno Senior High. Òun ni ọmọ James Frimpong àti Portia Lamptey. Samuel mú Medikal gẹ́gẹ́ bí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ nítorí ó fẹ́ràn láti máa kọ orin nípa àọn oníṣègùn òyìnbó, àwọn oníṣẹ́-abẹ, ilé-ìwòsàn àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Kí ó tó bẹ̀rẹ̀ orin kíkọ, ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí i agbábọ́ọ̀lù fún Ghana Premier League, fún ọ̀wọ́ Sekondi Hasaacas. Látàrí iṣẹ́ ribiribi rẹ̀, ó ti di gbajúgbajà olórin. Yàtọ̀ sí pé wọ́n yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ ní ọdún 2017, ó gba àmì-ẹ̀yẹ MTN 4Syte Video ní ọdún 2016 fún fọ́nrán orin rẹ̀.[6]
Ọdún | Ilé-iṣẹ́ | Olùgbà/Iṣẹ́ tí wọ́n yàn | Àmì-ẹ̀yẹ | Èsì | Ìtọ́ka |
---|---|---|---|---|---|
2021 | Vodafone Ghana Music Awards | Himself | Hiplife/Hip Hop Artist of the Year | Gbàá | [11] |
La Hustle rmx ft Joey B and Criss Waddle | Hip-Hop Song of the Year | Wọ́n pèé | |||
Himself | Artist of the year | Gbàá | |||
3Music Awards | Himself | Artist (MVP) of the Year | Wọ́n pèé | [12][13] | |
La Hustle rmx ft Joey B and Criss Waddle | Song of the Year | Wọ́n pèé | |||
Himself | Hiplife/Hip hop Act of the Year | Gbàá | |||
La Hustle ft Joey B | Hip Hop Song of the Year | Wọ́n pèé | |||
La Hustle rmx ft Joey B and Criss Waddle | Best Collaboration of the Year | Wọ́n pèé | |||
Himself | Rapper of the Year | Wọ́n pèé | |||
Himself | Most Streamed Act of the Year | Gbàá | |||
4syte Music Video Awards | 'Odo' ft. King Promise | Best Male Video | Wọ́n pèé | [14] | |
La Hustle ft Joey B | Best Edited Video | Wọ́n pèé | |||
Himself | Most Influential Artist | Gbàá | |||
La Hustle rmx ft Joey B and Criss Waddle | Big Tune | Wọ́n pèé | |||
La Hustle ft Joey B | Most Popular Video | Gbàá | |||
'Nonsense' | Best Hip Hop Video | Wọ́n pèé | |||
2020 | Vodafone Ghana Music Awards | Himself | Hiplife/Hiphop Artist of the Year | Gbàá | [15] |
"Omo Ada" | Hip-life song of the Year | Gbàá | |||
2019 | Vodafone Ghana Music Awards | Himself | Hip Hop Artist of the year | Gbàá | [16] |
Himself | Best Rapper of the year | Gbàá | |||
4syte Music Video Awards | "Omo Ada" | Best Special Effect Video | Gbàá | [17] | |
2017 | Vodafone Ghana Music Awards | Too Risky | Afro Pop Song Of The Year | Wọ́n pèé | [18] |
Confirm feat Sarkodie | Hip Hop Song Of The Year | Wọ́n pèé | |||
Himself | Hip-life/Hip Pop Artist Of The Year | Wọ́n pèé | |||
Himself | Best New Act | Wọ́n pèé | |||
Himself | Best Rapper of the year | Wọ́n pèé | |||
Confirm feat Sarkodie | Best Collaboration of the year | Wọ́n pèé | |||
Himself | Overall Artist of the year | Wọ́n pèé | |||
Exclusive Men of the Year Awards (EMY) | Discovery of The Year Category | Gbàá | |||
African Muzik Magazine Awards (AFRIMMA) | Best Newcomer Category | Gbàá | |||
2016 | MTN 4Syte Music Video Awards | Anthem | Best Discovery Video | Gbàá | [19] |
Ní oṣù Kẹta ọdún 2021, ó gba àmì-ẹ̀yẹ Hiplife/Hiphop Act of the Year ní 3Music Awards.[20]
Ní oṣù Kẹfà ọdún 2021, ó gba àmì-ẹ̀yẹ Hiplife/Hiphop Artist of the Year ní Vodafone Ghana Music Awards22.[21]