Mercy Achieng

Mercy Achieng
Personal information
OrúkọMercy Achieng Onyango
Ọjọ́ ìbí12 Oṣù Kẹjọ 1992 (1992-08-12) (ọmọ ọdún 32)
Ibi ọjọ́ibíKenya
Playing positionMidfielder
Club information
Current clubThika Queens FC
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
Thika Queens FC
National team
Kenya women's national football team
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals).

Mercy Achieng jẹ agbọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 12, óṣu August ni ọdun 1992. Agbabọọlu naa ṣere fun Thika Queens ati team apapọ ilẹ kenya[1][2][3].

  • Mercy kopa ninu Cup awọn obinrin ilẹ́ afirica ti agbaye, agbabọọlu na tun kopa ninu ere idije awọn obinrin COSAFA[4].
  1. https://footballkenya.org/ghana-black-queens-hold-harambee-starlets/mercy-achieng-goal-celebration/[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  2. https://m.goalzz.com/default.aspx?player=143937
  3. https://peoplepill.com/people/mercy-achieng
  4. https://globalsportsarchive.com/people/soccer/mercy-achieng/157014/