Mohammed Shaaba Lafiagi

Mohammed Shaaba Lafiagi jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti ọmọ Ilé-Ìgbìmọ̀ aṣòfin-àgbà ti Nàìjíríà.