Adébọ̀wálé "Débọ̀" Adébáyọ̀ (tí a bí ní ọjọ́ kẹta, oṣù karùn-ún, ọdún 1993),[1] tí orúkọ ìnagijẹ́ rè jẹ́ Mr Macaroni, jẹ́ òṣèré orílè-èdè Nàìjíríà, apanilérìn-ín, afèròhàn-lórí-èrọ-ayéllujára àti ajà-fẹ́tọ̀ọ́-ọmọnìyàn.[2][3][4] Ó kọ́ bí a ṣe ń pani lérìn-ín, ó sì di gbajúmọ̀ látàrí àwọn fọ́nrán kékèèké rẹ̀ tó ti máa ń fi ara rẹ̀ hàn gẹ́gẹ́ bíi olóṣèlú kan tó lówó, tó sì fẹ́ máa fẹ́ àwọn ọ̀dómọbìnrin, nínú àwọn eré yìí, orúkọ rẹ̀ máa ń jẹ́ "Daddy Wa". Ọ̀pọ̀ ènìyàn mọ Dẹ̀bọ̀ látàrí "Ooin", "Freaky freaky" àti "You are doing well" tó máa ń sọ ní gbogbo ìgbà nínú àwọn fọ́nrán rẹ̀.[5][6]
Ọdún
|
Àkọ́lé
|
Ipa
|
Ọ̀rọ̀ ní ṣókí
|
Ìtọ́kasí
|
2021
|
Ponzi
|
Uchenna
|
Ponzi jẹ́ fíìmù apanilẹ́rì-ín tó jáde ní ọdún 2022, tó dá lórí jíja ènìyàn ní jìbìtì.
|
[7][8]
|
Ayinla
|
Bayowa
|
Ayinla jẹ́ fíìmù olórin kan, tó fi ìgbésíayé olórin apala kan, Ayinla Yusuf, tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Ayinla Omowura hàn. Olórin yìí ni amúgbalẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀ tí orúkọ rè ń jẹ́ Bayewu gún paa ní ọjọ́ kẹfà, oṣù karùn-ún, ọdún 1980 ní ìlú Abẹ́òkúta.
|
[9][10]
|
2022
|
Survivors
|
|
Survivors jẹ́ ìtàn kan nípa àwọn òsìṣẹ́ mẹkáníìkì méjì tí wọ́n ń siṣẹ́ ní ẹ̀gbẹ́ títì, tí wọ́n ṣalábàápàdé ọ̀daràn David tó kọ́ wọ́n bí wọ́n tí ń jí ènìyàn gbé.
|
|
Aníkúlápó
|
Akanji
|
Aníkúlápó ṣàlàyé ìtàn Saro, arákùrin kan tó ń wá ọ̀nà àti jẹ àti mu kiri. Nínú ìrìn-àjò rẹ̀ ni ó ti pàdé ìyàwó ọba tó sì bẹ̀rẹ̀ sí ní fẹ́. Ìṣẹ̀lẹ̀ yìí ló ṣe ikú pa á, tí ẹyẹ kan tí a mọ̀ sí Àkàlà sì ra ẹ̀mí rẹ̀ padà.
|
[11]
|
Àkọ́lé
|
Ipa
|
Ìtókasí
|
Okirika
|
Alaga
|
[12]
|
Ile Alayo
|
Sweet Daddy
|
[13]
|
Flatmates
|
AK 47
|
[14]
|
The Johnsons
|
Casper
|
[15]
|
Ọdún
|
Àmì-ẹ̀yẹ̀
|
Ìsọ̀rí
|
Èsì
|
Reference
|
2018
|
Best of Nollywood Awards
|
style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé
|
[16]
|
2020
|
The Future Awards Africa
|
Gbàá
|
[17][18]
|
City People Music Award
|
Gbàá
|
[19]
|
2021
|
Net Honours
|
style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé
|
[20]
|
2022
|
Africa Magic Viewers' Choice Awards
|
style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé
|
[21][22]
|
2021
|
Gage Awards
|
Online Comedian of the Year
|
Won
|
[23]
|
- ↑ "Mr Macaroni, from Nigerian comedian to EndSARS activist". BBC News Pidgin. https://www.bbc.com/pidgin/media-56067641.
- ↑ "Adebowale Adedayo". IMDb. Retrieved 2022-09-27.
- ↑ "Mr Macaroni, others in marathon #EndSARSProtest in Lagos". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 9 October 2020. Retrieved 2 March 2021.
- ↑ "Broda Shaggi, Mr. Macaroni others top the list of digital content creators". Premium Times (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 29 January 2021. Retrieved 2 March 2021.
- ↑ "MrMacaroni (@mrmacaroni1) • Instagram photos and videos". www.instagram.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-09-27.
- ↑ "MR MACARONI - YouTube". www.youtube.com. Retrieved 2022-09-27.
- ↑ "Kayode Kasum: People's experience with MMM inspired 'Ponzi'". TheCable Lifestyle (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 9 March 2021. Retrieved 3 April 2021.
- ↑ Tv, Bn (1 March 2021). "Meet the Star-Studded Cast of Kayode Kasum's Comedy Film "Ponzi" + Watch the Trailer". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 3 April 2021.
- ↑ "Shades of a Tragic Hero". THISDAYLIVE (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 11 July 2021. Retrieved 14 July 2021.
- ↑ "Tunde Kelani commences movie on late Apala legend, Ayinla Omowura" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 11 December 2020. Retrieved 14 July 2021.
- ↑ "TRAILER: Kunle Remi, Sola Sobowale, Mr Macaroni star in ‘Anikulapo’". TheCable Lifestyle (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-08-15. Retrieved 2022-10-02.
- ↑ Online, Tribune (2021-09-23). "‘Okirika’ revamped as Nollywood stars, StarTimes collaborate on new comedy series". Tribune Online. Retrieved 2022-07-28.
- ↑ "Mr Macaroni, Broda Shaggi to star in “Ile Alayo” showing on StarTimes". Vanguard News. 2021-07-13. Retrieved 2022-07-28.
- ↑ "My Flatmates – Mr macaroni on this one as AK47". Abidon TV. 2021-10-16. Archived from the original on 2022-12-12. Retrieved 2022-07-28.
- ↑ "Mr Macaroni debuts on The Johnsons on Africa Magic". News Express Nigeria Website. 2021-05-16. Archived from the original on 2022-12-12. Retrieved 2022-07-28.
- ↑ Augoye, Jayne (10 December 2018). "BON Awards 2018: Tope Oshin, Tana Adelana win big" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 9 October 2021.
- ↑ "Drum rolls! 🥁 Introducing the Winners of The Future Awards Africa #TFAA2020". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 28 November 2020. Retrieved 2 March 2021.
- ↑ "FULL LIST: Mr. Macaroni, Rema, Sam Adeyemi win big at TFAA 2020". TheCable Lifestyle (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 28 November 2020. Retrieved 2 March 2021.
- ↑ "Winners Emerge At 2020 City People Music Awards [Full List]". City People Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 7 December 2020. Retrieved 2 March 2021.
- ↑ "Net Honours – The Class of 2021". Nigerian Entertainment Today (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 7 September 2021.
- ↑ "2022 Africa Magic Awards Nominees don land- See who dey list". BBC News Pidgin. https://www.bbc.com/pidgin/tori-60818021.
- ↑ "Stan Nze, Osas Ighodaro win big - Full list of all di winners from 2022 AMVCA". BBC News Pidgin. https://www.bbc.com/pidgin/tori-61452928.
- ↑ "Mr Macaroni, Nengi, Erica, Aisha Yesufu, Airopay make Gage awards 2021 nomination". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-02-22. Archived from the original on 2022-10-22. Retrieved 2022-10-27.