Nazir Ahmad Qasmi (wọ́n bí ní ogunjọ́ oṣu kẹ́fà 1964) jẹ́ onímọ̀ Islam ti Kashmiri Sunni ati Juri tí o jẹ Mufti àgbà fun Darul Uloom Raheemiyyah. Ó jẹ́ akẹkọọ jade ni Darul Uloom Deoband ati Imārat-e-Sharia; o jẹ́ ọ̀kan nínù àwọn ọmọ ẹgbẹ́ ìgbìmọ̀ alabójúto ofin gbogbo Mùsùlùmí ní India àti akọ̀wé àgbạ fún Majlis-e-Fiqui, Jammu ati Kashmir.
Nínú àwọn iṣẹ́ Qasmi ni ati ri, Mirzaiyat ka radd - Usūl awr Tarīqa-e-Behs àti Islam awr AIDS se tahaffuz ka tarīqa. Wọn nṣe àmúlò àlàkalẹ̀ ẹ̀sìn tí o ṣe fun Kashmir Uzma ní àwọn ọjọ́ jímọ̀.
Ìtàn Àkọsílẹ̀
Wọ́n bí Nazir Ahmad Qasmi ni ogúnjọ́ oṣu kẹfa, ọdún 1964 ní Bunjwar. Ó kọ́ Qurani ní àkọ́sórí ni Madrasa Asghria ni Deoband Ó sì kọ́ ẹ̀kọ́ àkọ́bẹ̀rẹ̀ èdè Arabic ni Madrasa Khādim al-Ulūm ni Muzaffarnagar. Ó parí ile ìwé rẹ̀ ní Darul Uloom Deoband nínú ẹ̀kọ́ dars-e-nizami ni ọdún 1404 A.H kí o tó wá tẹ̀síwájú fún ifta fún ọdun kan. Ẹ̀kọ́ ìmọ̀ òfin ni Qasmi yan laayo ni Imārat-e-Sharia in Patna. Lara àwọn olùkọ́ rẹ̀ ni Abdul Haq Azmi, Saeed Ahmad Palanpuri àti Riyasat Ali Bijnori.
Qasmi, lẹ́hìn tí o parí ẹ̀kọ́ rẹ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ olùkọ́ ní Darul Uloom Raheemiyyah. Ó jẹ́ Mufti àgbà ni Raheemiyyah tí i ṣe seminary, àti olùkọ́ àgbà ní Fiqhi, Jammu and Kashmir. àwọn ìdáhùn fiqhi rẹ̀ farahàn nínú àtẹ̀jáde Kashmir Uzma ni gbogbo Jimoh ọ̀kan lara iṣẹ́ akanṣe Kashmir.
Àgbékalẹ̀ òfin
Ni July 2017, níbi ìpàdé ìjíròrò ti "Ìbójútó àyíká ati ipa tí èsìn kó" ọlọ́jọ́ meji tí wọ́n gbékalẹ̀ láti ọwọ́ Central University ni Kashmir, ni ó ti sọ̀rò wípe "àkójọpọ̀ àti àbójútó omi àti àwon ohun àdáyéba yooku ni o jẹ́ ojúṣe àwọn ẹlẹ́sin fún gbogbo ẹ̀da ẹnikẹ́ni tí kò bá sì ṣe ti rú ofin ìsèdá." Nípa èdè Urdu, ó wípé, " kíkọ́, kíkọ àti mímọ̀ èdè Urdu jé dandan fún gbogbo Mùsùlùmi ní agbègbè naa (Kashmir)"
Qasmi's books include:
References
Itokasi
Kashmiri, Muhammad Anees (13 January 2023). "حضرت مفتی نذیر احمد صاحب ۔ حیات و خدمات" [Mufti Nazir Ahmad: Life and works]. Daily Udaan (in Urdu). No. 11. Retrieved 13 January 2023. The date of birth that Aftab Ghazi and other scholars have stated is wrong. I have referred to official documents and certificates of the Mufti and the birth date mentioned there is 20 June 1964 and not 1 June 1965.
Aftāb Ghāzi Qāsmi; Abdul Haseeb Qāsmi. Fuzala-e-Deoband Ki Fiqhi Khidmat [Services of the Graduates of Deoband in Islamic Jurisprudence] (in Urdu) (February 2011 ed.). p. 420.
Aftāb Ghāzi Qāsmi; Abdul Haseeb Qāsmi. Fuzala-e-Deoband Ki Fiqhi Khidmat [Services of the Graduates of Deoband in Islamic Jurisprudence] (in Urdu) (February 2011 ed.). p. 421.
"Mufti Nazir for social reformist groups". Greater Kashmir. 14 March 2015. Retrieved 5 September 2020.
"Mufti Nazir Qasmi to deliver Friday sermon at Qamarwari". Greater Kashmir. 31 March 2017. Retrieved 5 September 2020.
"جامعہ اشرف العلوم میں کنوکیشن: 20طلاب کی دستار بندی، علم حدیث کو کامیابی کے ساتھ مکمل کیا". Kashmir Uzma (in Urdu). 13 March 2022. Retrieved 4 June 2022.
"CUK's 2-day international conference on conservation and role of religion begins". Kashmir Vision. 6 July 2017. Retrieved 5 September 2020.
Faiz Qāziābādi (27 August 2023). Madāris awr Urdu [Madrassas and Urdu] (in Urdu) (2019 ed.). Delhi: Kitabi Dunya. p. 345. ISBN 978-93-84271-27-5.
Bibliography
Aftāb Ghāzi Qāsmi; Abdul Haseeb Qāsmi. "Mufti Nazīr Ahmad Kashmiri". Fuzala-e-Deoband Ki Fiqhi Khidmat [Services of the Graduates of Deoband in Islamic Jurisprudence] (in Urdu) (February 2011 ed.). Deoband: Kutub Khana Naimia. pp. 420–421.