Nasser Al Qasabi | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Nasser bin Qassim Al Qasabi ناصر بن قاسم القصبي 28 Oṣù Kọkànlá 1961 Riyadh, Saudi Arabia |
Iṣẹ́ | Actor, comedian |
Ìgbà iṣẹ́ | 1984–present |
Olólùfẹ́ | Badryah El-Bishr[1] |
Nasser bin Qassim Al Qasabi (Lárúbáwá: ناصر بن قاسم القصبي, tí wọ́n bí ní 28 November 1961 ní Riyadh, Saudi Arabia) jẹ́ òṣèrékùnrin ti ilẹ̀ Saudi Arabia.[2] Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré ní ọdún 1984, ó sì gbajúgbajà fún ẹ̀dá-ìtàn tó máa ń kó nínú eré Tash Ma Tash (Arabic: طاش ما طاش[3]). Ní ọdún 2012, Nasser wà lára àwọn adájọ́ fún ètò orí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán ti Arabs Got Talent.
|url-status=
ignored (help)