Ndidi Madu

Ndidi Madu
No. 12 – Broni
PositionForward
LeagueSerie A1
Personal information
Born17 Oṣù Kẹta 1989 (1989-03-17) (ọmọ ọdún 35)
Nashville, United States
NationalityAmerican/Nigerian
Listed height6 ft 2 in (1.88 m)
Career information
CollegeFlorida

Ndidi Madu (tí wọ́n bí ní March 17, 1989) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù alájùsáwọ̀n ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, àmọ́ tí wón bí sí ìlú America. Ó gbá bọ́ọ̀lù náà fún Broni àti Nigerian national team.[1]

Àwọn ìṣirò ti Florida statistics

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Orísun[2]

Legend
  GP Games played   GS  Games started  MPG  Minutes per game
 FG%  Field goal percentage  3P%  3-point field goal percentage  FT%  Free throw percentage
 RPG  Rebounds per game  APG  Assists per game  SPG  Steals per game
 BPG  Blocks per game  PPG  Points per game  Bold  Career high
Year Team GP Points FG% 3P% FT% RPG APG SPG BPG PPG
2007-08 Florida 1 3 50.0% 0.0% 50.0% 3.0 - - - 3.0
2008-09 Florida 26 62 51.0% 0.0% 50.0% 1.8 0.3 0.3 0.3 2.4
2009-10 Florida 32 121 35.0% 0.0% 59.5% 2.9 0.5 0.5 0.3 3.8
2010-11 Florida 35 251 45.4% 0.0% 76.7% 5.0 0.5 0.5 0.4 7.2
2011-12 Florida 33 165 39.7% 28.0% 61.5% 4.3 1.2 0.6 0.3 5.0
Career 127 481 41.9% 28.0% 62.5% 3.6 0.6 0.5 0.3 3.8

Iṣẹ́ rẹ̀ ní ẹgbẹ́ àgbáyé

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó kópa nínú ìdíje ti 2017 Women's Afrobasket.[3] Ó sì ní pọ́ìntì 3.9 pts, 3.9 RBG àti 1.6 APG nínú ìdíje náà.[4]

Ìfẹ̀yìntì rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní ọjọ́ karùndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹfà, ọdún 2018, Madu ṣe ìfilọ́lẹ̀ ìfẹ̀yìntì rè nínú gbígbá bọ́ọ̀lù alájùsáwọ̀n lórí ìtàkùn ẹ̀rọ-ayélujára,[5] ṣíwájú ìdíje ti 2018 FIBA Women's World cup ní ìlú Spain. Ó sọ ọ́ di mímọ̀ pé fífẹ̀yìntì yìí á ran òun lọ́wọ́ láti dojú lé ayé òun àti ìfẹ́ òun láti jẹ́ akọ́nimọ̀ọ́gbá fún ẹgbẹ́ tó gbé kalẹ̀, ìyẹ́n Team Madu Foundation, tó níṣe pẹ̀lú ìdàgbàsókè àwọn ọ̀dọ́.[6]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. FIBA profile
  2. "NCAA Statistics". web1.ncaa.org. Retrieved 2021-06-03. 
  3. "Ndidi MADU at the FIBA Women's Afrobasket 2017". FIBA.basketball. 
  4. "Ndidi Madu profile, FIBA Africa Champions Cup for Women 2015". FIBA.COM. Retrieved 2021-06-04. 
  5. "BasketballWithinBorders - Training the World, One Baller at a Time". 
  6. "Madu calls it quits ahead of FIBA Women's Basketball World Cup". FIBA.basketball.