Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 5 Oṣù Kejì 1978 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Nigeria | ||
Playing position | Forward | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
2004 | Delta Queens | ||
National team | |||
2004 | Nigeria women's national football team | 35 (?) | (15) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Nkechi Egbe jẹ́ agbábọ́ọ̀lú lóbìnrin tẹlẹ rí fún órilẹ èdè Nàìjíríà tí a bíní ọjọ́ karún, óṣu kejì ni ọdun 1978. Agbábọ́ọ̀lu náà ṣeré tẹlẹ rí fún team àpapọ àwọn obìnrin lórí bọ́ọ̀lú gẹgẹ bí ipò iwájú (orward)[1][2][3].