Nonso Amadi | |
---|---|
Amadi in 2018 | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Chinonso Obinna Amadi |
Ọjọ́ìbí | 1 Oṣù Kẹ̀sán 1995 Lagos, Nigeria |
Irú orin | |
Occupation(s) |
|
Years active | 2012 - present |
Labels | Universal Music Canada |
Associated acts | |
Website | nonsoamadi.com |
Chinonso Obinna Amadi[1] (tí wọ́n bí ní September 1, ọdún 1995) jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, akọrinkalẹ̀ àti agbórinjáde.[2] Ó jẹ́ olórin tó kọ́ ara rẹ̀ níṣẹ́ orin kíkọ, àti bí wọ́n ṣe ń gbórinjáde. Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ yìí nígbà tí ó wá ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti Covenant University, níbi tí ó ti kọ́ ẹ̀kọ́ nípa.[3]