Àárín | |||||||
Personal information | |||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|
Born | ọjọ́ kẹsan osù keje Ọdún 1995 Hayward, California, United States | ||||||
Nationality | Nàìjíríà-Amẹrika | ||||||
Listed height | 1.93 m (6 ft 4 in) | ||||||
Career information | |||||||
College | Duke University | ||||||
NBA draft | 2017 / Round: 3 / Pick: 31k overall | ||||||
Selected by the Atlanta Dream | |||||||
Medals
|
Oderah Obiageli Chidom tí a bí ní ọjọ́ kẹsan osù keje Ọdún 1995 jẹ́ ogbóǹtarìgì agbábọ́ọ̀lù ãláfọwọ́gbá sínú agbọ̀n ti ẹ̀ya Nàìjíríà-Amẹrika tí ó ńṣeré fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àwọn obìrin ti orílẹ̀ède Nàìjíríà .
Chidom ní àwọn àbúrò méjì: ọkùnrin kan, tí ó ń jẹ́ Arinze, àti obìnrin kan, tí ó ń jẹ́ Amara. Ó lọ sí Ilé-ìwé gíga Bishop O'Dowd ní Oakland, California, ó sì ṣeré ní bi ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù ãláfọwọ́gbá sínú agbọ̀n ti àwọn obìnrin ti ilé-ẹ̀kọ́ gíga.
Ó gbá bọ́ọ̀lù fún Ilé-ẹ̀kọ́ gíga Duke . Ó gbá bọ́ọ̀lù fún Tsmoki-Minsk. Ó buwọ́lùwé láti gbá bọ́ọ̀lù fún Angers.
Ó kópa nínú U17 Women's Basketball Championship. Ó tún kópa nínú 2019 EuroCup Women. Ó yege fún 2020 Summer Olympics