Okechukwu Oku | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Okechukwu Oku Enugu, Enugu State, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Orúkọ míràn | Okey Oku, the Oracle |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ | Film producer, director, cinematographer |
Ìgbà iṣẹ́ | 2001 – present |
Notable work | Bambitious |
Olólùfẹ́ | Queendalyn Oku |
Àwọn ọmọ | 3 |
Okechukwu Oku /θj/, tí ayé mọ̀ sí Okey Oku tàbí Oracle jẹ́ Olùdarí, olùṣe, cinematographer àti ọ̀kọọri. [1] ó Di gbajúmọ̀ látàrí fíìmù tí ó darí rẹ tí àkọlé rẹ ń jẹ́ Love and Oil tó jáde ní ọdún 2014, Burning Bridges ní ọdún 2014) àti Bambitious[2] (2014) tí àwọn Òṣeré bí Belinda Effah àti Daniel K Daniel náà kópa nínú eré náà.
Oku jẹ́ ọmọ bíbí ìpínlè Enugu ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, tí ó sì jẹ́ ọmọ tí wọ́n bí sì kejì nínú ọmọ mọ́kànlá tí àwọn òbí rẹ̀ Goddy àti Winifred Òkú bí. [3] Ó jẹ́ ọmọ íbò tí ó wá láti Ukpo ni agbègbè Dunukofia ni ìpínlè Anambra. [4] Baba rẹ̀, Goddy ńnẹ́ Gbajú-gbaà Olórin ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ní ọdún 1970s, tí ìyà rẹ̀ Wínifred sì jẹ́ òṣìṣẹ́ ìjọba tí ó ti fẹ̀yìntì. Ẹ̀gbọ́n Oku, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Udoka (Selebobo) Oku jẹ́ ẹni tí ó máa ń gbé orin jáde àti ọ̀kọọri. [5]
Oku bẹ̀rẹ̀ ilé ẹ̀kọ́ ni ilẹé ẹ̀kọ́ kékeré WT ni Enugu, tí ó sì tẹ síwájú láti lọ sí St. Charles Special Science School ni Onitsha, ní ìpínlè Anambra. Ní àárín kíkọ́ ẹ̀kọ́ àti lílọ sì ilé ìwé gíga Fáṣítì, oku sọ pé òun fẹ fi ìwé lè láti ṣíṣẹ Theatre. Nibẹ ni Oku tí bẹ̀rẹ̀ si nífẹ̀ẹ́ sì iṣẹ́ orin, tí ó sì kọ àwọn orin kììtẹ́nì[6] tí ó sì bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣe orin Jáde fún àwọn olórin ni gúúsù ìlà oòrùn ni orílè èdè Nàìjíríà,[7] Nípa báyìí ni ó padà di ẹni tí ó ń darí fídíò fún tẹlifíṣàn.
Oku ṣe ìgbéyàwó p pẹ̀lú Queendalyn OKu[8] Wọ́n sì bí ọmọ Mẹ́ta, tí Wọ́n sì ń gbé ní Enugu ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.
Feature Films
Year | Title | Major Cast | Role | Notes |
---|---|---|---|---|
2012 | Brother's Keeper | Omoni Oboli, Beverly Naya, Majid Michel, Barbara Soki | Cinematographer, Editor | Feature Film, nominated for the 2014 Nollywood Movies Awards for Best Editing and also for the 2013 Golden Icons Academy Movie Awards for Best Cinematography |
2012 | Last 3 Digits | Nonso Diobi, Sidney "Dr. Sid" Esiri, Yomi Blaq, Rachel Oniga | Director of Photography | Feature Film, won Best International Film Award |
2013 | Finding Mercy | Rita Dominic, Blossom Chukwujekwu, Chioma Akpotha | Director of Photography | Feature Film, Africa Movie Academy Award - Best Actor, Nollywood Movie Award - Best Rising Star, Nigerian Entertainment Award - Best Supporting Actor |
2014 | Love and Oil | Yul Edochie, Nuella Njubigbo, Jibola Dabo, Chinaza Ekezie | Director | Feature Film |
2014 | Burning Bridges | Ivie Okujaye, Ken Erics, Esther Audu | Director | Feature Film |
2014 | Bambitious[9] | Belinda Effah, Bucci Franklin, Daniel K Daniel, Ebele Okaro-Onyiuke | Director, Cinematographer, Editor | Feature Film, won multiple awards at the AAFMF |
2014 | Refugees | Yvonne Nelson, Belinda Effah, Diana Yekinni, Sandra Don Dufe, Ross Fleming, David Chin | Cinematographer | Feature Film, nominated for Best Cinematography at the 2016 AMVCA |
2014 | Chetanna | Chigozie Atuanya, Queen Nwokoye | DP, Editor | Feature Film, nominated for Best Igbo Film at the 2014 AMVCA and won GIAMA Awards for Best Indigenous Film |
2016 | Blackrose | Blossom Chukwujekwu, Ebele Okaro-Onyiuke, Lilian Echelon, Betty Bellor, William Iruoha (2Shotz) | Director | Feature Film |
2016 | A Better Family | Frederick Leonard, IK Ogbonna | Director, DP, Editor | Feature Film, released on YouTube |
2016 | Excess Luggage | IK Ogbonna, Mike Ezuronye, Queen Nwokoye | DP, Editor | Feature Film, nominated for the BON Awards for Best Comedy and a Toronto Film Festival Official Selection |
2016 | Jofran | IK Ogbonna, Lisa Omorodion | Producer, Director, DP, Editor | Feature Film, Africa Magic Original Film |
2016 | Let's hit the Streets | Alex Ekubo, IK Ogbonna | Director, DP, Editor | Feature Film |
2016 | Tommy and Kenny | Belinda Effah, Buchi Franklin | Director, DP, Editor | Feature Film |
2017 | Dirty Laundry | Zach Orji, Kalu Ikeagu | Proucer, Director, DP, Editor | Feature Film, Africa Magic Original Film |
2017 | American Driver | Evan King, Jim Iyke, Anita Chris, Nse Ikpe Etim, Nadia Buari, Emma Nyra, Ayo Makun, Laura Heuston, McPc the Comedian, Michael Tula, Andie Raven | Cinematographer | Feature Film, won Best Comedy at The People's Film Festival in 2017 |
2017 | Sarah's Epiphany | Daniella Okeke, Mike Ezuruonye, Anthony Monjaro | Director | Feature Film |
2017 | Levi | Ramsey Nouah, Nancy Isime, Deyemi Okanlawon | Director/Producer/Editor | Feature Film |
Music Videos
Year | Award | Category | Film | Result |
---|---|---|---|---|
2013 | 2013 Golden Icons Academy Movie Awards | Best Cinematography | Brother's Keeper | Wọ́n pèé |
2014 | 2014 Nollywood Movies Awards | Best Editing | Brother's Keeper | Wọ́n pèé |
2015 | Afrifimo Awards and Film /Music Festival[11] | Best Film Director | Bambitious | Gbàá |
2016 | Africa Magic Viewers' Choice Awards (AMVCA)[12] | Best Cinematographer for a Movie or TV Series | Refugees | Wọ́n pèé |
2018 | Zulu African Film Academy Awards (ZAFAA)[13] | Best Film Editor | Black Rose | Gbàá |
<ref>
tag; no text was provided for refs named AAFMF
<ref>
tag; no text was provided for refs named AMVCA