Okey Bakassi

Okey Bakassi
Bibi
Okechukwu Anthony Onyegbule




</br> 3 Oṣu Kẹwa Ọdun 1969



</br>
Ipinle Imo
Orilẹ-ede Nàìjíríà
Omiiran awọn orukọ okey bakassi
Omo ilu Nàìjíríà
Iṣẹ iṣe Apanilẹrin
Aaye ayelujara https://okeybakassi.com/

Okechukwu Anthony Onyegbule , tí gbogbo ènìyàn mọ̀ ssíOkey Bakassi tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹta Oṣù Kẹwàá Ọdún 1969 ní Ìpínlẹ̀ Ímò jẹ́ apanilẹ́rìnín àti òṣèré orí ìtàgé ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà . [1] [2] Ní 2014, ó gba Àmì ẹyẹ ''Òṣèré tí o dára julọ ni ipa ìtèwáju eré (Igbo)" ni ẹ̀dá 2014 ti Best of Nollywood Awards fún ipá rẹ nínú fíìmù Onye Ozi . [3] [4]