Okezie Victor Ikpeazu | |
---|---|
Fáìlì:Okezie Ikpeazu portrait.png | |
9th Gómìnà ìpínlẹ̀ Abia | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga May 29, 2015 | |
Deputy | Ude Oko Chukwu |
Asíwájú | Theodore Orji |
1st Deputy General Manager of Abia State Environmental Protection Agency | |
In office May 5, 2013 – October 10, 2014 | |
General Manager of the Abia State Passenger Integrated Manifest Scheme ASPIMS | |
In office March, 2011 – May 5, 2013 | |
Chairman of the Governing Council of Abia State College of Health Technology | |
In office June 2010 – May 29, 2011 | |
General Manager of Abia State Passenger Integrated Manifest Scheme ASPIMS | |
In office 2007–2009 | |
Chairman of Obingwa Local Government Area | |
In office 2002–2003 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 18 Oṣù Kẹ̀wá 1964 Abia State, Nigeria |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party (2002-2006, 2010–present) Progressive Peoples Alliance (2006-2010) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Nkechi Ikpeazu, (nee Nwakanma) |
Àwọn ọmọ | 4 |
Okezie Victor Ikpeazu (ojoibi 18 Osu Kewa 1964) ni Gomina Ipinle Abia lowolowo, o bo si ori aga ni May 29, 2015. O je omo egbe oselu Peoples Democratic Party.[1][2] Won tun diboyan si ipo gomina Ipinle Abia ninu idibo to waye ni March 9th, 2019.[3]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |