Olayemi Micheal "Yemi" Cardoso jẹ́ ọmọ Nigeria, òṣìṣẹ́ àgbà Ilé-ìfowópamọ́, oníṣòwò-àgbà ìpín-ìdókòwò, àti òní-lámèyító ètò àwùjọ tí Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu ṣẹ̀ṣẹ̀ yàn láti di Gómìnà Ilé-ìfowópamọ́-àpapọ̀ lọ́jọ́ 15 - 09 - 2023.[1][2] [3]. Ó ti fìgbà kan jẹ́ Alága Ilé-ìfowópamọ́ Citibank ní Nigeria, bẹ́ẹ̀ náà ló ti jẹ Kọmíṣànnà Lagos State Ministry of Economic Planning and Budget ní Ìpínlẹ̀ Èkó.[4][5][6]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |