Olu Oguibe | |
---|---|
![]() Olu Oguibe | |
Ìbí | 14 Oṣù Kẹ̀wá 1964 Aba, Eastern Nigeria |
Pápá | Conceptual art |
Ilé-ẹ̀kọ́ | University of Connecticut |
Ibi ẹ̀kọ́ | University of Nigeria, Nsukka School of Oriental and African Studies, University of London |
Doctoral advisor | John Picton |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | State of Connecticut Governor's Arts Award (2013); Arnold Bode Prize (2017) |
Olu Oguibe (tí wọ́n bí ní14 October 1964) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú America. Ó jẹ́ ayàwòrán àti onímọ̀.[1] Ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ní University of Connecticut, Storrs, ó sì tún jẹ́ ọmọ-ẹgbẹ́ àgbà ní Vera List Center for Art and Politics, ní New York City, àti Smithsonian Institution ní Washington, DC.[2]