Omo Ghetto: The Saga | |
---|---|
Fáìlì:Omo Ghetto The Saga Poster.jpg Promotional poster | |
Adarí | JJC Skillz Funke Akindele |
Olùgbékalẹ̀ | Funke Akindele Wendy Uwadiae Imasuen |
Àwọn òṣèré | Funke Akindele Chioma Akpotha Nancy Isime Eniola Badmus Bimbo Thomas Mercy Aigbe Deyemi Okanlawon Timini Egbuson Alex Ekubo |
Ìyàwòrán sinimá | John Dems |
Olóòtú | JJC Skillz Valentine Chukwuma Adeyemi Adeshomade |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | Scene One Productions |
Olùpín | FilmOne Distribution |
Déètì àgbéjáde |
|
Àkókò | 110 minutes |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Èdè | English, Yoruba, Igbo, Hausa, Nigerian Pidgin |
Owó àrígbàwọlé | ₦636.1 million[1] |
Omo Ghetto: The Saga tí a tún mọ̀ sí Omo Ghetto 2[2] jẹ́ fíìmù àwàdà oníjàgídíjàgan tí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó jáde ní ọdún 2020, tí Funke Akindele àti JJC Skillz ṣe adarí rẹ̀[3]. Àwọn gbajúgbajà fíìmù náà ni Funke Akindele, Chioma Akpota, Nancy Isime, Eniola Badmus, Bimbo Thomas, Deyemi Okanlawon àti Mercy Aigbe. Èyí ni fíìmù apá kejì ti Omo Ghetto, àti pé ó jẹ́ ìtẹ̀síwájú fíìmùOmo Ghetto tó jáde ní ọdún 2010[4]. Ní ọjọ́ 26 oṣù January, ọdún 2021, nígbà tí fíìmù náà kọ́kọ́ jáde wọ́n rí tó ₦468 million, ní èyí tó ju ti The Wedding Party lọ. Ó sì mu kó jẹ́ fíìmù àgbéléwò tó ní èrè tó pọ̀l jù lọ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà[5][6].
Akindele sọ ọ di mímọ̀ pé kí wọ́n tó bẹ̀rẹ̀ apá kejì fíìmù yìí ní oṣù kejì ọdún 2020, òun ṣe àgbéjáde àwọn àwòrán rẹ̀ àtijọ́ tó yà pẹ̀lú Eniola Badmus. Àwòrán yíyà fún fíìmù náà bẹ̀rẹ̀ ní oṣù February, ọdún 2020[7]. Ètò fíìmù yìí náà tún jẹ́ ìbẹ̀ẹ̀rẹ̀ ìpọwọ́ṣiṣẹ́ pọ̀ òun àti ọkọ rẹ̀ JJC Skillz, gẹ́gé bí olùdarí fíìmù náà[8]. Díẹ̀ lára yíya ìràn fíìmù náà wáyé ní Dubai, United Arab Emirates àti pé àrùn COVID-19 pandemic kó ipa lára fíìmù náà[9].
Ọdún | Àmì-ẹ̀yẹ | Ìsọ̀rí | Olùgbà | Èsì | Ìtọ́ka |
---|---|---|---|---|---|
2021 | 17th Africa Movie Academy Awards|Africa Movie Academy Awards | Best Actress in a Leading Role | Funke Akindele | Wọ́n pèé | [10] |
Achievement in Editing | Omo Ghetto | Wọ́n pèé | |||
Best Nigerian Film | Wọ́n pèé | ||||
2022 | 2022 Africa Magic Viewers' Choice Awards|Africa Magic Viewers' Choice Awards | Best Actress in A Comedy | Funke Akindele | Gbàá | [11][12] |
Best Costume Designer | Wọ́n pèé | ||||
Best Actor in A Comedy | Deyemi Okanlawon | Wọ́n pèé | |||
Best Supporting Actress in Movie/ Television Series | Chioma Chukwuka | Wọ́n pèé | |||
Best Make-Up | Abiodun Balogun | Gbàá | |||
Best Picture Editor | JJC Skillz, Valentine Chkukwuma, Adeyemi Shomade | Wọ́n pèé | |||
Best Sound Editor | Puffy Tee | Wọ́n pèé | |||
Best Movie West Africa | Funke Akindele & JJC Skillz | Wọ́n pèé | |||
Best Overall Movie | Wọ́n pèé |
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)
|url-status=
ignored (help)