Orezi | |
---|---|
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Esegine Orezi Allen |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | Dat GehnGehn Guy[1] |
Ọjọ́ìbí | 28 Oṣù Kẹta 1986 Delta State, Nigeria |
Irú orin | |
Occupation(s) |
|
Years active | 2009–present |
Labels |
|
Associated acts | |
Website | iamorezi.com |
Esegine Allen (tí wọ́n bí ní 28 March 1986), tí ọ̀pọ̀ ènìyàn mọ̀ sí Orezi, jẹ́ olórin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tó wá láti Ìpínlẹ̀ Dẹ́ltà. Ó di gbajúgbajà nígbà tó kọ orin tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "Rihanna" ní ọdún 2013.[2][3]