Oyin Adejobi | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 1926 Nigeria |
Aláìsí | 2000 (ọmọ ọdún 73–74) |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ |
|
Gbajúmọ̀ fún | Orogun Adedigba |
Olólùfẹ́ | Grace Oyin-Adejobi |
Oloye Oyin Adejobi (1926–2000)[1] jẹ́ òǹṣèré ni orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Orúkọ rẹ̀, Oyin tunmọ si "Honey" ni èdè gẹ̀ẹ́sì.[2] Ó kọ oríṣiríṣi itan, o si kópa nínú eré orí ìtàgé Yorùbá lori ẹrọ amóhùnmáwòrán ati ninu fíìmù. Ọ ṣe ìgbéyàwó pẹlu òṣèré Grace Oyin-Adejobi, ti wọn sì jọ wà pọ̀ títí di ọjọ́ ikú rẹ̀.[3]
Pàápàá jùlọ, o gbajumo fún eré agbelewo "Orogun Adedigba", eyi ti o jẹ ìtàn ìgbésí ayé rẹ̀. O tún ní eré amóhùnmáwòrán ọ̀sẹ̀ẹ̀ṣẹ̀ 'Kootu Ashipa', eyi tí o ma n nṣe ni adari ilé iṣẹ amóhùnmáwòrán Naijiria (Nigerian Television Authority) ni abala ti ìlú Ibadan. A sọ gbọ̀gàn iṣèré 'Oyin Adejobi' ti o gbajúmọ̀ lẹyìn orúkọ rẹ̀.[4]