Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Onyinyechi Salome Zogg[1] | ||
Ọjọ́ ìbí | 3 Oṣù Kẹta 1997[2] | ||
Ibi ọjọ́ibí | Bern, Switzerland | ||
Ìga | 1.72 m[2] | ||
Playing position | Defender[2] | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Young Boys | 16 | (1) | |
Femina Kickers Worb | |||
FC Bethlehem | |||
2019–2021 | Zürich | 35 | (4) |
2021–2022 | ASJ Soyaux | 11 | (0) |
2022–2023 | Turbine Potsdam | 3 | (0) |
National team‡ | |||
2021– | Nigeria | 2 | (0) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 7 May 2023. † Appearances (Goals). |
Onyinyechi Salome Zogg (tí wọ́n bí ní 3 March 1997) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù tó ń gbá bọ́ọ̀lù nípò alátakò. Ìlú Switzerland ni wọ́n bí i sí, ó sì ṣojú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ìdíje gbogboogbò.
Wọ́n bí Zogg sí ìlú Bern.[4] Bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Switzerland, ìyá rẹ̀ sì jẹ́ ọmọ Nàìjíríà.
Ilé-ìwé Monroe College ni Zogg lọ, ní United States.[4]
Zogg gbá bọ́ọ̀lù fún ẹgbẹ́ BSC Young Boys, Femina Kickers Worb, FC Bethlehem àti Zürich ní Switzerland.
Zogg ṣe àfihàn ẹlẹ́ẹ̀kejì fún Nàìjíríà ní 10 June 2021 ní ayò ọlọ́rẹ̀ẹ́jọ́rẹ̀ẹ́, sí 0–1 sí Jamaica.[5]