Pablo César | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Pablo César 26 Oṣù Kejì 1962 Buenos Aires, Argentina |
Orílẹ̀-èdè | Argentine |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Fundación Universidad del Cine |
Iṣẹ́ | Director, producer, writer, actor, editor |
Ìgbà iṣẹ́ | 1977–present |
Pablo César (tí wọ́n bí ní 26 Oṣù Kínní, Ọdún 1962), jẹ́ olùdarí eré ọmọ orílẹ̀-èdè Argẹntínà.[1][2] Ó ti lọ́wọ́sí sinimá ilẹ̀ Áfríkà pẹ̀lú dídarí àwọn eré bíi Equinox, the Garden of the Roses, Los dioses de agua àti Aphrodite, the Garden of the Perfumes.[3]