Paparazzi: Eye in the Dark

Paparazzi: Eye in the Dark
Fáìlì:Paparazzi Eye in the Dark - Poster.jpg
AdaríBayo Akinfemi
Olùgbékalẹ̀Clarice Kulah
Koby Maxwell
Òǹkọ̀wéKojo Edu Ansah
Àwọn òṣèréVan Vicker
Syr Law
Koby Maxwell
Tchidi Chikere
Chet Anekwe
JJ Bunny
Bayo Akinfemi
OrinKoby Maxwell
Blaise Tangelo
Paul G
Irina
Ìyàwòrán sinimáBlack Magic Tim
OlóòtúBlack Magic Tim
Ilé-iṣẹ́ fíìmùG.M.P.
RVI Motion Media
OlùpínGreat Moments Productions
Déètì àgbéjáde
  • Oṣù Kejì 12, 2011 (2011-02-12)
Àkókò144 minutes
Orílẹ̀-èdèNigeria
ÈdèEnglish

Paparazzi: Eye in the Dark jẹ́ fíìmù ajẹmọ́fẹ̀ẹ́ ti ọdún 2011,[1][2] èyí tí olùdarí rẹ̀ jẹ́ Bayo Akinfemi[3], àwọn akópa sì ni Van Vicker,[4][5] Koby Maxwell, Tchidi Chikere, Syr Law,[6][7] JJ Bunny[8] àti Chet Anekwe. FÍìmù náà dá lórí ìrìn-àjò ayàwòrán kan tó ṣèṣì lọ ya àwòrán ìpànìyàn kàyéfì kan. Wọ́n ṣàgbèjáde rẹ̀ ní February, 2011.[9][10][11][12][13][14] Àwọn aṣagbátẹrù fíìmù náà gba aṣagbátẹrù fíìmù kan tó jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè America, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ (Tim "Black Magic Tim" Wilson)[15] láti jẹ́ ayafọ́nrán àti aṣàtúntò eré náà.[16]

Ayàwòrán tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Rich Amarah (Van Vicker)[17] ni lọ́kàn láti fi iṣẹ́ ìyàwòrán rẹ̀ di ọlọ́lá, àmọ́ ó wá di ẹni tí ń ya àwòrán ní kọ̀rọ̀, èyí sì lówó gidi lórí. Látàrí títa àwọn àwòrán rẹ̀ fún ìwé-ìròyìn, ó ní àǹfààní láti máa jókòó ti àwọn ọlọ́lá àti ọlọ́rọ̀. Gbajúgbajà ayàwòrán ilẹ̀ Ghana tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Mr. Maxx (Koby Maxwell) wà ní òkè, ó sì ní pòhùngbẹ fún àṣeyọrí ṣíṣe, èyí sì mu kí ó ṣèṣì ya àwòràn ìpànìyàn kan. Ìṣẹ̀lẹ̀ yìí tàn kálẹ̀, ó sì mú kí ẹ̀mí rẹ̀ wà léwu.

  • Van Vicker gẹ́gẹ́ bí i Rich Amarah
  • Koby Maxwell gẹ́gẹ́ bí i Mr Maxx
  • Tchidi Chikere gẹ́gẹ́ bí i Jimmy
  • Syr Law gẹ́gẹ́ bí i Pearl
  • Chet Anekwe gẹ́gẹ́ bí i Davis
  • Bayo Akinfemi gẹ́gẹ́ bí i Pat
  • JJ Bunny gẹ́gẹ́ bí i Jackie
  • Princess Pursia gẹ́gẹ́ bí i Donna

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Ghanacelebrities. "Sandra Rose Talks About Paparazzi". Retrieved 7 March 2011. 
  2. Rose, Sandra. "Sandra Rose Talks About Paparazzi". Retrieved 7 March 2011. 
  3. "Nollywood Director Bayo Akinfemi Talks About Paparazzi". Retrieved 7 March 2011. 
  4. Golden Icons, "Nollywood USA- Paparazzi" "Nollywood USA – Paparazzi | Golden Icons". Archived from the original on 2011-05-10. Retrieved 2011-02-24.  Unknown parameter |url-status= ignored (help) Golden Icons, Inc.(2011)
  5. TheAfricans, "Van Vicker ' Paparazzi ' EYE IN THE DARK Movie Review" [1] Beeafrican.com, Published September 13, 2010.
  6. Syr Law wins NAFCA award. "Entertainment in Ghana". Archived from the original on 25 April 2012. Retrieved 10 October 2011.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  7. Lotten B. "Hollywood Actress Syr Law talks about Paparazzi Premiere". Archived from the original on 2016-03-04. Retrieved 2023-10-09. 
  8. Lotten B Show. "Nollywood USA Star JJ Bunny talks about Paparazzi". Archived from the original on 13 July 2011. Retrieved 7 March 2011. 
  9. www.filmafrique.com. "Paparazzi in California". Archived from the original on 2 April 2012. Retrieved 21 September 2011. 
  10. Great Moments Productions, (2011)"PAPARAZZI: EYE IN THE DARK - Great Moments Productions". Archived from the original on 2011-03-14. Retrieved 2011-03-24.  Unknown parameter |url-status= ignored (help) Official Website
  11. African Angels Network in association with BeeAfrican.com (2011) [2] Archived 2011-03-08 at the Wayback Machine. Movie Tickets/Promos, Retrieved 2011-02-24
  12. "Koby Interview about Films US Tour". All News Ghana. Retrieved 7 March 2011. 
  13. Metz, Nina (24 February 2011). "Paparazzi shaping African cinema". Chicago Tribune. Archived from the original on 12 July 2012. https://archive.today/20120712041737/http://articles.chicagotribune.com/2011-02-24/entertainment/ct-mov-0225-chicago-closeup-20110224_1_native-heads-83rd-academy-awards-rabbit-hole/3. Retrieved 7 March 2011. 
  14. "US AD Agency Plan B talks about Paparazzi". Plan B Ad Agency. Archived from the original on 30 April 2011. Retrieved 7 March 2011.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  15. "M2 Show Tim Wilson Changes look of Nollywood". YouTube. Retrieved 7 March 2011. 
  16. Lotten B, (2011)[3] Archived 2018-12-29 at the Wayback Machine. "Tim Wilson -Cinematographer for Paparazzi", Lotten B Show, Published 2-17-2011.
  17. "Nollywood A-List Actor Van Vicker Talks about His Role". Vimeo Interview. Retrieved 7 March 2011.