Sadé Adéníran jẹ́ àràmàdà ònkọ̀wé ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjírìa, a bíi ńi ọdún 1960. Àràmàdà ìwé rẹ̀ àkọ́kọ́, Fojúinú Wòyí gba àmì ẹ̀yẹ ònkọ̀wé àgbáyé ti ọdún 2008 fún ìwé àkọ́kọ́ tó dára jùlọ ní Afíríkà. Fojúinú Wòyí jẹ́ àtẹ̀jáde àkọ́kọ́ nípasè ònkọ̀wé náà fún rara rẹ̀. Ó ń gbé ní Lo ndọ́nù[1], Ó tún jẹ́ òṣèré fíìmù. [2]