Saheed Aderinto | |
---|---|
![]() | |
Ọjọ́ìbí | Ibadan, Oyo State, Nigeria | Oṣù Kínní 22, 1979
Orílẹ̀-èdè | Nigerian, American |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Ibadan, University of Texas, Austin |
Iṣẹ́ | professor, historian, writer |
Employer | Florida International University |
Gbajúmọ̀ fún | Historical scholarship |
Notable work | Animality and Colonial Subjecthood: The Human and Nonhuman Creatures of Nigeria; Guns and Society in Colonial Nigeria |
Olólùfẹ́ | Olamide Aderinto |
Àwọn ọmọ | Itandola • Itandayo |
Awards | 2023 Dan David Prize; Nigerian Studies Association Book Prize for "When Sex Threatened the State." |
Website | saheedaderinto.com |
Saheed Aderinto (tí wọ́n bí ní January 22, 1979) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú America, ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n tó ń kọ́ History and African and African Diaspora Studies ni Florida International University. Bákan náà ló jẹ́ òǹkọ̀wé tó ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmi-ẹ̀yẹ. Òun ni olùṣẹ̀dásílẹ̀ Lagos Studies Association.[1] NÍ oṣù February, ọdún 2023, Aderinto gba ẹ̀bùn $300,000, èyí tó jẹ́ ti Dan David Prize.[2][3] Ó ti ṣàtẹ̀jáde ìwé mẹ́jọ, jọ́nà mẹ́rìndínlógójì, átíkú ogójì àti ìríwísí sí ìwé ogún.[4]