Saworoide jẹ́ eré àgbéléwò tí Tunde Kelani darí àti tí Mainframe Films àti Television Production ṣe àgbéjáde rẹ̀ ní ọdún 1999.
Saworoide ṣe àfihàn ètò àṣà yorùbá pípẹ́ kan ní ìlú Jogbo níbi tí èèyàn kò lè jẹ oba láìjé pé èèyàn tó tọ́ lú ìlu saworoide.[1]