Sew the Winter to My Skin jẹ fiimu iṣere odun 2018 ti South Africa ti Jahmil X.T. Qubeka[1]jẹ oludari. Won se afiihan re ni abala ti Contemporary World Cinema ni Toronto International Film Festival[2]ti odun 2018. A yan fun ipo ere ajeji to daara julo ni orilede South Africa ni ayeye 91st Academy Awards, sugbon yiyan re fun nipari obosi.[3][4]