Special Anti-Robbery Squad tí òpòlopò ènìyàn mó sí SARS jé aka Olopa télè rí tí a dá kalè ní odun 1992 láti dojuko iwuwa odaran [1] sùgbón tí opin dé bá ní ojó kokanla, osù kewa, odun 2020(11 Oct. 2020)[2] léyìn iwode ifehonuhan láti owo awon odo Nàìjíríà tí a mo sí iwode "fopin sí SARS"
Àwon odo Nàìjirià bèrè iwode ifehonuhan náà bèrè ní 0ct 2020 [3] ni ìgbà tí fiimu bí àwon olopa SARS kan se pa okunrin kan àti bi won se gbe okò rè lo farahan lórí ìkànnì ayelujara [4] èyi mú ìjoba apapo Nàìjirià fopinsi eka SARS ni Oct 11, 2020 [5]