Sunkanmi Omobolanle | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 1 March 1981 Oyo State, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹ̀kọ́ | B.sc Business Administration, Olabisi Onabanjo University |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Olabisi Onabanjo University |
Iṣẹ́ | actor |
Notable work | Kakanjo |
Olólùfẹ́ | Abimbola Bakare |
Parent(s) | Sunday Omobolanle (father) |
Sunkanmi Omobolanle jẹ́ òṣèrékùnrin ilẹ̀ Nàìjíríà, àti olùdarí fíìmù.[1][2][3]
Ọjọ́ kìíní oṣụ̀ kẹta ọdún 1981 ni wọ́n bí i. Ìlú Ilora ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tó wà ní apá Ìwọ̀-oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà ni ó ti wá.[4] Òun ni ọmọ gbajúgbajà òṣèrékùnrin tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Sunday Omobolanle, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí "Baba Luwee".[5] Ilé-ìwé Nigerian Military School ni ó ti kàwé kí ó tó lọ sí Yunifásítì Olabisi Onabanjo, níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè bachelor's degree nínú ìmọ̀ Business administration.[6] Ó ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú Abimbola Bakare, ní ọdún 2011.[7] Ó sì ti ṣe àfihàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ fíìmù Nàìjíríà, bẹ́ẹ̀ náà ni ó ti dárí ọ̀pọ̀ fíìmù.[8]
|url-status=
ignored (help)