Sàbúrì Bíòbákú | |
---|---|
Ìbí | June 16, 1918 Abẹ́òkúta |
Aláìsí | 2001 |
Ará ìlẹ̀ | Ọmọ Nàìjíríà |
Ẹ̀yà | Yoruba |
Pápá | History |
Ilé-ẹ̀kọ́ | University of Ibadan University of Lagos |
Ibi ẹ̀kọ́ | Trinity College, Cambridge |
Ó gbajúmọ̀ fún | Yorùbá historiography |
Religious stance | Islam |
Sàbúrì Oladeni Bíòbákú (1918 - 2001) jẹ́ Ọ̀mọ̀wé ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà. Bíòbákú jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ̀n nínú ìmọ̀ Ìtàn Samuel Johnson nínú ìwádìí ọ̀rọ̀ -ìtàn Yorùbá.[1][2]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |