Túndé Aládéṣe jẹ́ olùkọ̀tàn tí ó sì tún ti gba àmì-ẹ̀yẹ ti Africa Movie Academy Award for Best Actress in a Leading Role ní ọdún 2018.[1]Ó ti kọ ìtàn ti a 70 night drama fún MTV Shuga filmed by the actors themselves over four countries, explaining and set during the coronavirus lockdown .
Aládéṣe ti nífẹ́ sí eré orí-ìtàgé láti ìgbà tí ó ti wà ní ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bérẹ̀ níbi tí ó ti dara pọ̀ mọ́ àwùjọ ẹgbẹ́ òṣèré tí ó sì fẹ́ràn orin kíkọ pẹ̀llú. Ó kẹ́kọ́ nìmọ̀ nípa eré-oníṣe nínú èdè Gẹ̀ẹ́sì (English Literature) ní Yunifásitì Ìbàdàn .[2] Ó tú kẹ́òọ́ nípa eré orí-ìtàgé ní Met Fi School ní ìlú Lóndọ̀nù,.[2]
Aládéṣe ti kọ ìtàn fún Edge of Paradise àti Tinsel.[3] She was the head writer for the series Hotel Majestic.[4] Àjọ [YNaija]] kàá mọ́ àwọn ọmọ ogójì ọdún tí wọ́n ń kópa ribiribi ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[5] Ní ọdún 2018, ipa tí Aládéṣe kó nínú eré The Lost Cafe' gẹ́gẹ́ bí Kenneth Gyang ni wọ́n fi yàn án fún Africa Movie Academy Awards gẹ́gẹ́ bí òṣèré tó peregedé jùlọ .[6] Aládéṣe ma ń kọ eré àtìgbàdégbà fún MTV Shuga, nígbà tí wọ́n pe àwọn ọlọ́kan-ò-jọkan eré Ṣúgà ní Shuga Down South. Ó kọ ìsọ̀rí méjì fún iṣẹ́ náà ṣáájú kí wọ́n tó yàn án gẹ́gẹ́ bí olóòtú àgbà fún iṣẹ́ àkànṣe náà. [7] Ní àsìkò àjàkálẹ̀ àrùn Covid-19, wọ́n ní kí ó kọ ìsọ̀rí eré olójojúmọ́ fún MTV Shuga Alone Together kí ó sì sọ ipa àti ìdààmú tí àrùn Kòrónà ń mú bá àwọn ènìyàn. Wọ́n fi eré náà hàn ní ogúnjọ́ oṣù Kẹrin ọdún 2020.[8]Wọ́n ṣe eré náà ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, South Africa àti Cote D’Ivoire.[7] The series was planned to last for 65 episodes.[2]