Adetayo Oluwatosin Olusegun Adio Aduramigba Iretioluwa Edun (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù karùn-ún, ọdún 1998) jẹ́ ògbóǹtarìgì agbábọ́ọ̀lù Gẹ̀ẹ́sì tó máa ń gbá bọ́ọ̀lù náà ni ipò midfielder fún Charlton Athletic.
Ìyá kan tó wá láti Saint Vincent àti The Grenadines àti bàbá kan tó wá láti orílẹ-èdè Nàìjíríà, tó ń lọ sí Enfield grammar school, ló bí Ẹdun ní Islington tó wà ní orílẹ-èdè London.
Ní Ọjọ́ kẹ́sàn án oṣù kẹ́jọ, ọdún 2016, On 9 August 2016, Edun made his professional debut in a League Cup match against Leyton Orient.[3]
́́Ní ọjọ́ kẹẹ̀ta oṣù kẹẹ̀jọ ọdún 2018, Edun fọwọ́ sí ìwé láti dara pọ̀ mọ́ ikọ̀ egbẹ́ Bọ́ọ̀lù Ipswich Town nígbà tí ó parí àdéhùn rẹ pẹ̀lú Fulham. . [1] Ó gbá àmì ayò 2-2 Pẹ̀lú ikọ̀ Blackburn Rovers ní ọjọ́ 4 oṣù 8 ọdún 2018. [2]Àwọn ikọ̀ Fulman tún pè é padà ní ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ́n oṣù Kejìlá ọdún 2018 látàrí ojú tí ó ń dùn ún, ó parí ìfọ́wọ́síwèé rẹ lẹ́yìn ìgbà tí ó fara hàn ní ẹ̀mẹẹ̀fà.. [3]
Lẹ́yìn ìgbà tí ó kúrò ní Fulham, Edun fọwọ́ sí wèé ọdún méjì àti àbọ̀ pẹ̀lú líìgì one club Lincoln city ní ọjọ́ kẹwàá oṣù kìíní ọdún 2020.O peregedé nínú ayò náà èyí tí ó gbá láti díje pẹ̀lú ẹgbẹ́ liverpool ní ìdíje kẹẹ̀ta tí ife EFL ní ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹsàn-án ọdún 2020.
Ní ọjọ́ kanlélọ́gbọ̀n oṣù kẹ́jọ ọdún 2021, Edun yóò darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ EFL Championship side Blackburn Rovers.[9]
Ní ọjọ́ karùnlélógún oṣù kẹfà ọdún 2023, Edun darapọ̀ mọ́ League One side Charlton Athletic fún ọdún méjì. [4]
Wọ́n bí Edun ní ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì ó sì jẹ́ ti St Vincent àti ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó ti ṣaṣojú England ní under 17, under 18, under 19 ati lábé ipele 20.
A yan Edun láti ṣe aṣojú England labẹ-17 ni 2015 UEFA European Under-17 Championship àti 2015 FIFA U-17 World Cup .
Edun wà nínú ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù England labẹ-19 fún ìdíje 2017 UEFA European Under-19 Championship . wọ́n yọọ́ Kúrò ní ìparí lẹ́yìn tí ó gbà káádì pupa méjì, síbẹ̀síbẹ̀ England wáyè láti ṣẹ́gun Portugal . Lẹ́yìn náà ni wọ́n fi Edun sínú ẹgbẹ́ ìdíje náà.
Club | Season | League | FA Cup | EFL Cup | Other | Total | ||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Division | Apps | Goals | Apps | Goals | Apps | Goals | Apps | Goals | Apps | Goals | ||
Fulham | 2016–17 | Championship | 0 | 0 | 0 | 0 | 3 | 0 | — | 3 | 0 | |
2017–18 | 2 | 0 | 0 | 0 | 2 | 0 | — | 4 | 0 | |||
2018–19 | Premier League | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | — | 0 | 0 | ||
2019–20 | Championship | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | — | 0 | 0 | ||
Total | 2 | 0 | 0 | 0 | 5 | 0 | 0 | 0 | 7 | 0 | ||
Ipswich Town (loan) | 2018–19[5] | Championship | 6 | 1 | 0 | 0 | 1 | 0 | — | 7 | 1 | |
Lincoln City | 2019–20[6] | League One | 6 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 6 | 0 |
2020–21 | 42 | 1 | 2 | 0 | 2 | 1 | 9[lower-alpha 1] | 0 | 55 | 2 | ||
2021–22 | 4 | 1 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 0 | 4 | 1 | ||
Total | 52 | 2 | 2 | 0 | 3 | 1 | 9 | 0 | 65 | 3 | ||
Blackburn Rovers | 2021–22[7] | Championship | 20 | 0 | 1 | 0 | 0 | 0 | — | 21 | 0 | |
2022–23 | 8 | 0 | 1 | 0 | 4 | 0 | — | 13 | 0 | |||
Total | 28 | 0 | 2 | 0 | 4 | 0 | 0 | 0 | 34 | 0 | ||
Charlton Athletic | 2023–24 | League One | 26 | 0 | 3 | 0 | 1 | 0 | 3[lower-alpha 2] | 0 | 33 | 0 |
Career total | 114 | 3 | 7 | 0 | 13 | 1 | 12 | 0 | 146 | 4 |
England U19
Individual
<ref>
tag; no text was provided for refs named TE18
<ref>
tag; no text was provided for refs named TE19
<ref>
tag; no text was provided for refs named TE21
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tags exist for a group named "lower-alpha", but no corresponding <references group="lower-alpha"/>
tag was found