The Narrow Path | |
---|---|
[[File:Fáìlì:Movie poster for The Narrow Path.jpg|200px|alt=]] | |
Adarí | Túndé Kèlání |
Òǹkọ̀wé | Túndé Kèlání Niji Akanni |
Àwọn òṣèré | Sola Asedeko Ayo Badmus Khabirat Kafidipe |
Orin | Beautiful Nubia Seun Owoaje |
Ìyàwòrán sinimá | Lukaan Abdulrahman Tunde Kelani |
Olóòtú | Mumin Wale Kelani Frank Efe Patrick |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | Mainframe Film and Television Productions |
Olùpín | Mainframe Film and Television Productions |
Déètì àgbéjáde | 2006 |
Àkókò | 95 minutes |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Èdè | English and Yoruba |
The Narrow Path Ni eré oníṣẹ́ tí wọ́n gbé jáde ní ọdún 2006, tí alàgbà Túndé Kèlání gbé jáde tí ó sì darí rẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Wọ́n ṣe àfàyọ eré yí láti inú ìwé onítàn The Virgin, ìwé tí Bayo Adebowale ke jáde.[2][3][4]
Eré yí ni ó sọ nípa ìṣòro tí ẹ̀dá ìtàn kan tí ó jẹ́ Awẹ̀ró tí ó ní láti mú ọ̀kan nínú àwọn ọkùnrin méjì Ọdẹ́jìmí ati Lápàdé tí ó jẹ́ ọmọ ọdẹ tí wọ́n ń dẹnu ifẹ́ kọ. [5][6][7]