The Department | |
---|---|
Adarí | Rẹ̀mí Vaughan-Richards |
Olùgbékalẹ̀ | Uduak Oguamanam
|
Òǹkọ̀wé | Chinaza Onuzo |
Àwọn òṣèré |
|
Ìyàwòrán sinimá | Ayọ̀ọlá Ireyọ̀mí |
Olóòtú | Níyì Akinmọ̀layan |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù |
|
Olùpín | FilmOne Distributions |
Déètì àgbéjáde | 2015/01/30 |
Àkókò | 104 minutes |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Èdè | Gẹ̀ẹ́sì |
The Department jẹ́ fíìmù Nàìjíríà ọdún 2015 tó dá lórí ròmáàsì Ọ̀daràn ákísọ̀nù tí Olùdarí rẹ̀ jẹ́ Rẹ́mì Vaughan-Richards, àwọn olórí Òṣèré ni: Majid Michel, OC Ukeje, Desmond Elliot, Osas Ighodaro, Jídé Kosoko, ṣeun Akíndélé, Somkele Iyamah, Funky Mallam and Kenneth Okolie[1][2] Fíìmù náà kọ́kọ́ jẹ́ ìfọwọ́wọ̀ Inkblot Productions àti Closer Pictures,[3][4] ó jẹ́ Atọ́kùn láti ọwọ́ Uduak Oguamanam àti Chinaza Onuzo.[5]
Fíìmù náà sọ ìtàn nípa ọ̀wọ̀ àṣírí kan tó ní àwọn ẹgbẹ́ oníṣòwò, gẹ́gẹ́ bíi àwọn ẹgbẹ́ Ọ̀daràn ọ̀wọ̀ yìí máa ń fi àbùkù kàn àwọn òṣìṣẹ́ ńlá láti ta ilé-iṣẹ́ wọn fún ọ̀gá wọn (Jídé Kòsókó). Olólùfẹ́ méjì (Majid Michel àti Osas Ighodaro) náà wá àyè láti fi iṣẹ́ náà lẹ̀, ṣùgbọ́n ọ̀wọ́ yìí fẹ́ pè wọ́n padà fún iṣẹ́ tó gbẹ́yìn. Obìnrin lára àwọn olólùfẹ́ yìí náà gbà lẹ́yìn ọkọ rẹ̀, tó ma padà fi iṣẹ́ náà fún ọ̀wọ́ náà láti má à tún ìgbéyàwó òun àti ọkọ rẹ̀ ká.