Timi Dakolo | |
---|---|
Background information | |
Ọjọ́ìbí | 20 Oṣù Kínní 1981 Accra, Ghana |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Bayelsa State, Nigeria |
Irú orin | Soul music |
Occupation(s) | Singer |
Instruments | Vocals |
Years active | 2007–present |
Labels | Virgin Records (UMG) |
Website | timidakolo.com |
Timi Dakolo (tí a bí ní ọjọ́ ogún, oṣù kìíní, ọdún 1981) jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, akọrin-kalẹ̀ àti agbórin-jáde.[1] Ó kópa nínú ìdíje Idols West Africa ní ọdún 2007, ó sì jáde pẹ̀lú ipò kìíní.[2] Lẹ́yìn aṣeyọrí rẹ̀ yìí, ó tẹwọ́bọ̀wé iṣẹ́ pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ Sony BMG, ó sì gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀bùn mìíràn.[3][4]