Prince Tony Momoh | |
---|---|
Minister of Information and Culture | |
In office 1986–1990 | |
Arọ́pò | Alex Akinyele |
Chairman, Congress for Progressive Change | |
In office January 2011 – 1 February 2021 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Auchi, Colonial Nigeria | 27 Oṣù Kẹrin 1939
Aláìsí | 1 February 2021 | (ọmọ ọdún 81)
Website | http://www.tonymomoh.com |
Ọmọ oba Tony Momoh (tí a bí ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣu kẹrin ọdún 1939, tó sì kú ní ọjọ́ kínní oṣù kejì ọdún 2021)[1] jẹ́ akọ̀ròyìn Nàijíríà àti olóṣèlú kan tí ó jẹ́ Mínísítà fún Ìfitónilétí àti Àṣà Nàijíríà (láti ọdún 1986 wọ 1990) lákòókò ìjọba ológun ti Ọ̀gágun Ibrahim Babangida.
A bí Momoh ní ọjọ́ 27 Oṣù Kẹrin ọdún 1939 ní Auchi, ìjọba ìpínlẹ̀ Edo. Ó jẹ́ ọmọ karùn-ún lé lọ́gọ́jọ (165) ti Ọba Momoh I ti Auchi.[2]
Ó lọ sí Ilé-ìwé Ìjọba Auchi (1949–1954) àti Ilé-ìwé Anglican Okpe (1954). Momoh jẹ́ Olùkọ́ni Akẹ́ẹ̀kọ́ ní Ilé-ìwé Anglican, Auchi (Oṣù kińní- Oṣù kejìlá 1955) ati Olukọni ni Ile-iwe Anglican, Ubuneke, Ivbiaro, Ijọba Ibile Owan (January 1958 - Kejìlá 1959).[3]
|url-status=
ignored (help)