Tunde Olukotun | |
---|---|
Ìbí | Oyekunle Ayinde Olukotun London, England |
Pápá | high-performance computer architecture; parallel computing |
Ilé-ẹ̀kọ́ | Stanford University |
Doctoral advisor | Trevor Mudge |
Ó gbajúmọ̀ fún |
|
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí |
|
Oyekunle Ayinde "Kunle" Olukotun jẹ́ ọmọ Britain tó tún tan mọ́ ilẹ̀ Nàìjíríà[1] jẹ́ onímọ̀ ẹ̀rọ, tó sì tún jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ti Cadence Design Systems Professor ní Stanford School of Engineering, ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmọ̀ Electrical Engineering àti Computer Science ní Stanford University, àti olùdarí láàbù Stanford Pervasive Parallelism.[2] [3][4]
|url-status=
ignored (help)