Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Ngozi Eucharia Uche | ||
Ọjọ́ ìbí | 18 Oṣù Kẹfà 1973 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Mbaise, Nigeria | ||
National team | |||
Nigeria women's national football team | |||
Teams managed | |||
Nigeria women's national football team | |||
† Appearances (Goals). |
Uche Eucharia Ngozi pronunciation (ọjọ́-ìbí 18 June 1973 ní Mbaise, Imo state, Nàìjíríà ) jé footballer Orílẹ-èdè Nàìjíríà nígbà kán ri àti olórí àgbá Nigeria Women's national football team télè. Òun ni olùrànlọ́wọ́ obìnrin àkọ́kọ́ fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ó sì tún jẹ́ akọ́nilẹ́kọ̀ọ́ obìnrin àkọ́kọ́ fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù orílẹ̀-èdè Nàìjíríà . Lọ́wọ́lọ́wọ́ ó jẹ́ FIFA àti Confederation of African Football olùkó. Uche dàgbà ní Owerri, Nigeria .
Ẹni àkọ́kọ́ nínú àwọn ọmọ márùn-ún, a tọ́ ọ dàgbà ní àyíká ọ̀pọ̀ ẹ̀kọ́. Ó lọ sí ilé-ìwé Secondary Girls Egbu, Owerri, ṣáájú kí o tó lọ sí Delta State University . Lákokò tí ó wà ní ilé-ìwé gírámà, Uche bẹ̀rẹ̀ football. Ní àwọn ọjẹ́ eré rẹ̀, ó ṣeré fún Bendel Striking Queens, lọ́wọ́lọ́wọ́ Edo Queens, Rivers Angels, àti Ufuoma Babes, Delta Queens lóòní. Lẹ́hìnnáà ó gbà bọ́ọ̀lù fún ẹgbẹ́ Super Falcons tí orílẹ-èdè Nàìjíríà. Ní àwọn ọjọ́ ìṣère rẹ̀, ó di obìnrin Áfíríkà àkọkọ ti yóò jẹ́ orúkọ Top Scorer nínú ìdíje káríayé, bákannáà obìnrin Nàìjíríà àkọkọ tí ó gbà àyò ìjà àgbáyé wọlé, Nigeria vs Ghana 1999. Ó tẹ̀síwájú ó sí dí olùkọ́ní obìnrin àkọkọ wọ́n. Ní ọdún 2010, ó di olùkọ́ni Obìnrin àkọkọ láti gbà àkọlé African Women's Championship. [1] Wọ́n lé e kúrò ní oṣù kẹwàá ọdún 2011 lẹ́yìn tí Nàìjíríà kùnà láti tóótun fún 2012 Summer olympics . [2]
FIFA kìlọ̀ fún Uche fún àwọn ọ̀rọ̀ tí ó sọ lákokò ìdíje 2011FIFA Women's World Cup, nínú èyítí o pe homosexuality ni “concerning issue” tí ó kàn pàtàkì àwọn òṣèré rẹ̀. [3] [4]
Olukọni