Up North | |
---|---|
Fáìlì:Up North Poster.jpg Theatrical release poster | |
Adarí | Tope Oshin |
Olùgbékalẹ̀ |
|
Àwọn òṣèré | Àdàkọ:Startplainlist |
Orin |
|
Ìyàwòrán sinimá | Pindem Lot Kagho Bichop Idhebor |
Olóòtú | Banjo Onyekachi Ayodele |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | Anakle Films Inkblot Productions |
Olùpín | FilmOne Entertainment |
Déètì àgbéjáde | 28 December 2018 |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Èdè |
|
Owó àrígbàwọlé | ₦94 million[1] |
Up North jẹ́ fíìmù àgbéléwò tí ó jáde láti ọwọ́ Anakle Films and Inkblot Productions [2]ní ọdún 2018 ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí diTope Oshin[3] ṣe olùdarí rẹ̀. Naz Onuzo and Bunmi Ajakaiye ló kọ ire náà látàrí itan tí Editi Effiong kọ.[4] Ní ìlú Bauchi ni wọ́n ya iṣẹ́ náà, pẹ̀lú yíya ọ̀sẹ̀ kan ní ìlú Èkó Lagos.[5]